{ "welcome": "Ẹ káàbọ sí", "cake_wallet": "Cake Wallet", "first_wallet_text": "Àpamọ́wọ́ t'á fi Monero, Bitcoin, Ethereum, Litecoin, àti Haven pamọ́ wà pa", "please_make_selection": "Ẹ jọ̀wọ́, yàn dá àpamọ́wọ́ yín tàbí dá àpamọ́wọ́ yín padà n’ísàlẹ̀.", "create_new": "Dá àpamọ́wọ́ tuntun", "restore_wallet": "Mú àpamọ́wọ́ padà", "monero_com": "Monero.com latí ọwọ́ Cake Wallet", "monero_com_wallet_text": "Àpamọ́wọ́ Monero wà pa", "haven_app": "Haven latí ọwọ́ Cake Wallet", "haven_app_wallet_text": "Àpamọ́wọ́ Haven wà pa", "accounts": "Àwọn àkáǹtì", "edit": "Pààrọ̀", "account": "Àkáǹtì", "add": "Fikún", "address_book": "Ìwé Àdírẹ́sì", "contact": "Olùbásọ̀rọ̀", "please_select": "Ẹ jọ̀wọ́ yàn:", "cancel": "Fagi lé e", "ok": "Ó dáa", "contact_name": "Orúkọ olùbásọ̀rọ̀", "reset": "Tún ṣe", "save": "Pamọ́", "address_remove_contact": "Yọ olùbásọ̀rọ̀ kúrò", "address_remove_content": "Ṣó dá ẹ lójú pé ẹ fẹ́ yọ olùbásọ̀rọ̀ yíyàn kúrò?", "authenticated": "A ti jẹ́rìísí yín", "authentication": "Ìfẹ̀rílàdí", "failed_authentication": "Ìfẹ̀rílàdí pipòfo. ${state_error}", "wallet_menu": "Mẹ́nù", "Blocks_remaining": "Àkójọpọ̀ ${status} kikù", "please_try_to_connect_to_another_node": "Ẹ jọ̀wọ́, gbìyànjú dárapọ̀ mọ́ apẹka mìíràn yí wọlé", "xmr_hidden": "Bìbò", "xmr_available_balance": "Owó tó wà ḿbí", "xmr_full_balance": "Ìyókù owó", "send": "Ránṣẹ́", "receive": "Gbà", "transactions": "Àwọn àránṣẹ́", "incoming": "Wọ́n tó ń bọ̀", "outgoing": "Wọ́n tó ń jáde", "transactions_by_date": "Àwọn àránṣẹ́ t'á ti fi aago ṣa", "trades": "Àwọn pàṣípààrọ̀", "filter_by": "Ṣẹ́ láti", "today": "Lénìí", "yesterday": "Lánàá", "received": "Owó t'á ti gbà", "sent": "Owó t'á ti ránṣẹ́", "pending": " pípẹ́", "rescan": "Tún Wá", "reconnect": "Ṣe àtúnse", "wallets": "Àwọn àpamọ́wọ́", "show_seed": "Wo hóró", "show_keys": "Wo hóró / àwọn kọ́kọ́rọ́", "address_book_menu": "Ìwé Àdírẹ́sì", "reconnection": "Àtúnṣe", "reconnect_alert_text": "Ṣó dá ẹ lójú pé ẹ fẹ́ ṣe àtúnse?", "exchange": "Pàṣípààrọ̀", "clear": "Pa gbogbo nǹkan", "refund_address": "Àdírẹ́sì t'ẹ́ gba owó sí", "change_exchange_provider": "Pààrọ̀ Ilé Ìfowóṣòwò", "you_will_send": "Ṣe pàṣípààrọ̀ láti", "you_will_get": "Ṣe pàṣípààrọ̀ sí", "amount_is_guaranteed": "ó di dandan pé owó á wọlé", "amount_is_estimate": "Ìdíyelé ni iye tó ń bọ̀", "powered_by": "Láti ọwọ́ ${title}", "error": "Àṣìṣe", "estimated": "Ó tó a fojú díwọ̀n", "min_value": "kò gbọ́dọ̀ kéré ju ${value} ${currency}", "max_value": "kò gbọ́dọ̀ tóbi ju ${value} ${currency}", "change_currency": "Pààrọ̀ irú owó", "overwrite_amount": "Pààrọ̀ iye owó", "qr_payment_amount": "Iye owó t'á ránṣé wà nínú àmì ìlujá yìí. Ṣé ẹ fẹ́ pààrọ̀ ẹ̀?", "copy_id": "Ṣẹ̀dà àmì ìdánimọ̀", "exchange_result_write_down_trade_id": "Ẹ jọ̀wọ́, kọ àmì ìdánimọ̀ pàṣípààrọ̀ sílẹ̀ kí tẹ̀síwájú.", "trade_id": "Pàṣípààrọ̀ àmì ìdánimọ̀:", "copied_to_clipboard": "Jíjí wò sí àtẹ àkọsílẹ̀", "saved_the_trade_id": "Mo ti pamọ́ àmì ìdánimọ̀ pàṣípààrọ̀", "fetching": "ń wá", "id": "Àmì Ìdánimọ̀: ", "amount": "Iye: ", "payment_id": "Àmì ìdánimọ̀ àránṣẹ́: ", "status": "Tó ń ṣẹlẹ̀: ", "offer_expires_in": "Ìrònúdábàá máa gbẹ́mìí mì ní: ", "trade_is_powered_by": "${provider} ń fikún pàṣípààrọ̀ yìí lágbára", "copy_address": "Ṣẹ̀dà àdírẹ́sì", "exchange_result_confirm": "T'ẹ́ bá tẹ̀ jẹ́rìí, ẹ máa fi ${fetchingLabel} ${from} ránṣẹ́ láti àpamọ́wọ́ yín t'á pe ${walletName} sí àdírẹ́sì t'ó ṣàfihàn òun lísàlẹ̀. Tàbí ẹ lè fi àpamọ́wọ́ mìíràn yín ránṣẹ́ sí àdírẹ́sì / àmì ìlujá lísàlẹ̀.\n\nẸ jọ̀wọ́ tẹ̀ jẹ́rìí́ tẹ̀síwájú tàbí padà sọ́dọ̀ pààrọ̀ iye náà.", "exchange_result_description": "Ẹ gbọ́dọ̀ ránṣẹ́ iye owó tó pọ̀ jù ${fetchingLabel} ${from} sí àdírẹ́sì tó ṣàfihàn òun lójú tó ń bọ̀. T'ẹ́ bá fi iye tí kò pọ̀ jù ${fetchingLabel} ${from}, a kò lè pàṣípààrọ̀ ẹ̀. A sì kò lè dá a padà fún yín.", "exchange_result_write_down_ID": "*Ẹ jọ̀wọ́, ṣẹ̀dà àmì ìdánimọ̀ yín tó ṣàfihàn òun lókè.", "confirm": "Jẹ́rìísí", "confirm_sending": "Jẹ́rìí sí ránṣẹ́", "commit_transaction_amount_fee": "Jẹ́rìí sí àránṣẹ́\nOwó: ${amount}\nIye àfikún: ${fee}", "sending": "Ó ń ránṣẹ́", "transaction_sent": "Ẹ ti ránṣẹ́ ẹ̀!", "expired": "Kíkú", "time": "${minutes}ìṣj ${seconds}ìṣs", "send_xmr": "Fi XMR ránṣẹ́", "exchange_new_template": "Àwòṣe títun", "faq": "Àwọn ìbéèrè l'a máa ń bèèrè", "enter_your_pin": "Tẹ̀ òǹkà ìdánimọ̀ àdáni yín", "loading_your_wallet": "A ń ṣí àpamọ́wọ́ yín", "new_wallet": "Àpamọ́wọ́ títun", "wallet_name": "Orúkọ àpamọ́wọ́", "continue_text": "Tẹ̀síwájú", "choose_wallet_currency": "Ẹ jọ̀wọ́, yàn irú owó ti àpamọ́wọ́ yín:", "node_new": "Apẹka títun", "node_address": "Àdírẹ́sì apẹka", "node_port": "Ojú ìkànpọ̀ apẹka", "login": "Orúkọ", "password": "Ọ̀rọ̀ aṣínà", "nodes": "Àwọn apẹka", "node_reset_settings_title": "Tún àwọn ààtò ṣe", "nodes_list_reset_to_default_message": "Ṣé ó dá yín lójú pé ẹ fẹ́ yí àwọn ààtò padà?", "change_current_node": "Ṣé ó dá yín lójú pé ẹ fẹ́ pààrọ̀ apẹka lọ́wọ́ sí ${node}?", "change": "Pààrọ̀", "remove_node": "Yọ apẹka kúrò", "remove_node_message": "Ṣé ó da yín lójú pé ẹ fẹ́ yọ apẹka lọwọ́ kúrò?", "remove": "Yọ ọ́ kúrò", "delete": "Pa á", "add_new_node": "Fi apẹka kún", "change_current_node_title": "Pààrọ̀ apẹka lọwọ́", "node_test": "Dánwò", "node_connection_successful": "Ìkànpọ̀ ti dára", "node_connection_failed": "Ìkànpọ̀ ti kùnà", "new_node_testing": "A ń dán apẹka títun wò", "use": "Lo", "digit_pin": "-díjíìtì òǹkà ìdánimọ̀ àdáni", "share_address": "Pín àdírẹ́sì", "receive_amount": "Iye", "subaddresses": "Àwọn àdírẹ́sì kékeré", "addresses": "Àwọn àdírẹ́sì", "scan_qr_code": "Yan QR koodu", "qr_fullscreen": "Àmì ìlujá túbọ̀ máa tóbi tí o bá tẹ̀", "rename": "Pààrọ̀ orúkọ", "choose_account": "Yan àkáǹtì", "create_new_account": "Dá àkáǹtì títun", "accounts_subaddresses": "Àwọn àkáǹtì àti àwọn àdírẹ́sì kékeré", "restore_restore_wallet": "Mú àpamọ́wọ́ padà", "restore_title_from_seed_keys": "Fi hóró/kọ́kọ́rọ́ mú padà", "restore_description_from_seed_keys": "Mú àpamọ́wọ́ yín padà láti hóró/kọ́kọ́rọ́ t'ẹ́ ti pamọ́ sí ibi láìléwu", "restore_next": "Tẹ̀síwájú", "restore_title_from_backup": "Fi ẹ̀dà nípamọ́ mú padà", "restore_description_from_backup": "Ẹ lè fi ẹ̀dà nípamọ́ yín mú odindi Cake Wallet áàpù padà.", "restore_seed_keys_restore": "Mú hóró/kọ́kọ́rọ́ padà", "restore_title_from_seed": "Fi hóró mú padà", "restore_description_from_seed": "Ẹ mú àpamọ́wọ́ yín padà láti àkànpọ̀ ọlọ́rọ̀ ẹ̀ẹ̀marùndínlọgbọ̀n tàbí ti mẹ́talá.", "restore_title_from_keys": "Fi kọ́kọ́rọ́ ṣẹ̀dá", "restore_description_from_keys": "Mú àpamọ́wọ́ yín padà láti àwọn àtẹ̀ nípamọ́ láti àwọn kọ́kọ́rọ́ àdáni yín", "restore_wallet_name": "Orúkọ àpamọ́wọ́", "restore_address": "Àdírẹ́sì", "restore_view_key_private": "kọ́kọ́rọ́ ìrán àdáni", "restore_spend_key_private": "kọ́kọ́rọ́ àdáni fún níná", "restore_recover": "Mú padà", "restore_wallet_restore_description": "Ìṣapẹrẹ mú àpamọ́wọ́ padà", "restore_new_seed": "Hóró títun", "restore_active_seed": "Hóró lọ́wọ́", "restore_bitcoin_description_from_seed": "Mú àpamọ́wọ́ yín padà láti àkànpọ̀ ọlọ́rọ̀ ẹ̀ẹ̀mẹrinlélógun", "restore_bitcoin_description_from_keys": "Mú àpamọ́wọ́ yín padà láti ọ̀rọ̀ WIF t'á ti dá láti kọ́kọ́rọ́ àdáni yín", "restore_bitcoin_title_from_keys": "Mú padà láti WIF", "restore_from_date_or_blockheight": "Ẹ jọ̀wọ́, tẹ̀ ìgbà ọjọ́ díẹ̀ k'ẹ́ tó ti dá àpamọ́wọ́ yìí. Tàbí ẹ lè tẹ̀ ẹ́ t'ẹ́ bá mọ gíga àkójọpọ̀.", "seed_reminder": "Ẹ jọ̀wọ́, kọ wọnyí sílẹ̀ k'ẹ́ tó pàdánù ẹ̀rọ ìbánisọ̀rọ̀ yín", "seed_title": "Hóró", "seed_share": "Pín hóró", "copy": "Ṣẹ̀dà", "seed_language_choose": "Ẹ jọ̀wọ́ yan èdè hóró:", "seed_choose": "Yan èdè hóró", "seed_language_next": "Tẹ̀síwájú", "seed_language_english": "Èdè Gẹ̀ẹ́sì", "seed_language_chinese": "Èdè Ṣáínà", "seed_language_dutch": "Èdè Nẹ́dálaǹdì", "seed_language_german": "Èdè Jámánì", "seed_language_japanese": "Èdè Jẹ́páànì", "seed_language_portuguese": "Èdè Potogí", "seed_language_russian": "Èdè Rọ́síà", "seed_language_spanish": "Èdè Sípéènì", "seed_language_french": "Èdè Fránsì", "seed_language_italian": "Èdè Itálíà", "send_title": "Ránṣẹ́", "send_your_wallet": "Àpamọ́wọ́ yín", "send_address": "${cryptoCurrency} àdírẹ́sì", "send_payment_id": "Àmì ìdánimọ̀ àránṣẹ́ (ìyàn nìyí)", "all": "Gbogbo", "send_error_minimum_value": "Ránṣẹ́ owó kò kéré dé 0.01", "send_error_currency": "Ó yẹ kí òǹkà dá wà nínu iye", "send_estimated_fee": "Iye àfikún l'a fojú díwọ̀n:", "send_priority": "${transactionPriority} agbára ni owó àfikún lọ́wọ́lọ́wọ́.\nẸ lè pààrọ̀ iye agbára t'ẹ fikún àránṣẹ́ lórí àwọn ààtò", "send_creating_transaction": "Ńṣe àránṣẹ́", "send_templates": "Àwọn àwòṣe", "send_new": "Títun", "send_amount": "Iye:", "send_fee": "Owó àfikún:", "send_name": "Orúkọ", "got_it": "Ó dáa", "send_sending": "Ń Ránṣẹ́...", "send_success": "A ti ránṣẹ́ ${crypto} yín dáadáa", "settings_title": "Àwọn ààtò", "settings_nodes": "Àwọn apẹka", "settings_current_node": "Apẹka lọ́wọ́lọ́wó", "settings_wallets": "Àwọn àpamọ́wọ́", "settings_display_balance": "Ṣàfihàn ìyókù owó", "settings_currency": "Iye owó", "settings_fee_priority": "Bí iye àfikún ṣe ṣe pàtàkì", "settings_save_recipient_address": "Pamọ́ àdírẹ́sì olùgbà", "settings_personal": "Àdáni", "settings_change_pin": "Pààrọ̀ òǹkà ìdánimọ̀ àdáni", "settings_change_language": "Pààrọ̀ èdè", "settings_allow_biometrical_authentication": "Fi àyè gba ìfẹ̀rílàdí biometrical", "settings_dark_mode": "Ṣókùnkùn Áápù", "settings_transactions": "Àwọn àránṣẹ́", "settings_trades": "Àwọn pàṣípààrọ̀", "settings_display_on_dashboard_list": "Ṣàfihàn lórí àkọsílẹ̀ tá fihàn", "settings_all": "Gbogbo", "settings_only_trades": "Àwọn pàṣípààrọ̀ nìkan", "settings_only_transactions": "Àwọn àránṣẹ́ nìkan", "settings_none": "Kòsóhun", "settings_support": "Ìranlọ́wọ́", "settings_terms_and_conditions": "Àwọn Òfin àti àwọn Àjọrò", "pin_is_incorrect": "òǹkà ìdánimọ̀ àdáni kò yẹ́", "setup_pin": "Setup òǹkà ìdánimọ̀ àdáni", "enter_your_pin_again": "Tún òǹkà ìdánimọ̀ àdáni yín tẹ̀", "setup_successful": "Òǹkà ìdánimọ̀ àdáni yín ti ṣe!", "wallet_keys": "Hóró/kọ́kọ́rọ́ àpamọ́wọ́", "wallet_seed": "Hóró àpamọ́wọ́", "private_key": "Kọ́kọ́rọ́ àdáni", "public_key": "Kọ́kọ́rọ́ tó kò àdáni", "view_key_private": "Kọ́kọ́rọ́ ìwò (àdáni)", "view_key_public": "Kọ́kọ́rọ́ ìwò (kò àdáni)", "spend_key_private": "Kọ́kọ́rọ́ sísan (àdáni)", "spend_key_public": "Kọ́kọ́rọ́ sísan (kò àdáni)", "copied_key_to_clipboard": "Ti ṣeda ${key} sí àtẹ àkọsílẹ̀", "new_subaddress_title": "Àdírẹ́sì títun", "new_subaddress_label_name": "Orúkọ", "new_subaddress_create": "Ṣe é", "address_label": "Orúkọ àdírẹ́sì", "subaddress_title": "Àkọsílẹ̀ ni nínú àwọn àdírẹ́sì tíwọn rẹ̀lẹ̀", "trade_details_title": "Ìsọfúnni pàṣípààrọ̀", "trade_details_id": "Àmì ìdánimọ̀:", "trade_details_state": "Tó ń ṣẹlẹ̀", "trade_details_fetching": "Ń mú wá", "trade_details_provider": "Ilé pàṣípààrọ̀", "trade_details_created_at": "Ṣíṣe ní", "trade_details_pair": "Àwọn irú owó t'á pàṣípààrọ̀ jọ", "trade_details_copied": "Ti ṣeda ${title} sí àtẹ àkọsílẹ̀", "trade_history_title": "Ìtan pàṣípààrọ̀", "transaction_details_title": "Àránṣẹ́ ìsọfúnni", "transaction_details_transaction_id": "Àmì ìdánimọ̀ àránṣẹ́", "transaction_details_date": "Ìgbà", "transaction_details_height": "Gíga", "transaction_details_amount": "Iye owó", "transaction_details_fee": "Iye àfikún", "transaction_details_copied": "A ṣeda ${title} sí àkọsílẹ̀", "transaction_details_recipient_address": "Àwọn àdírẹ́sì olùgbà", "wallet_list_title": "Àpamọ́wọ́ Monero", "wallet_list_create_new_wallet": "Ṣe àpamọ́wọ́ títun", "wallet_list_edit_wallet": "Ṣatunkọ apamọwọ", "wallet_list_wallet_name": "Orukọ apamọwọ", "wallet_list_restore_wallet": "Restore àpamọ́wọ́", "wallet_list_load_wallet": "Load àpamọ́wọ́", "wallet_list_loading_wallet": "Ń ṣí àpamọ́wọ́ ${wallet_name}", "wallet_list_failed_to_load": "Ti kùnà ṣí́ àpamọ́wọ́ ${wallet_name}. ${error}", "wallet_list_removing_wallet": "Ń yọ àpamọ́wọ́ ${wallet_name} kúrò", "wallet_list_failed_to_remove": "Ti kùnà yọ ${wallet_name} àpamọ́wọ́ kúrò. ${error}", "widgets_address": "Àdírẹ́sì", "widgets_restore_from_blockheight": "Dá padà sípò láti gíga àkójọpọ̀", "widgets_restore_from_date": "Dá padà sípò láti ìgbà", "widgets_or": "tàbí", "widgets_seed": "Hóró", "router_no_route": "Ọ̀nà kò sí fún ${name}", "error_text_account_name": "Orúkọ àkáǹtì lè ni nìkan nínú ẹyọ ọ̀rọ̀ àti òǹkà\nGígun rẹ̀ kò gbọ́dọ̀ kéré ju oókan. Gígun rẹ̀ sì kò gbọ́dọ̀ tóbi ju márùndínlógún.", "error_text_contact_name": "Orúkọ olùbásọ̀rọ̀ kò lè ni nínú ` , ' \" ẹyọ ọ̀rọ̀.\nIye ẹyọ ọ̀rọ̀ kò gbọ́dọ̀ kéré ju oókan. Ó sì kò gbọ́dọ̀ tóbi ju méjìlélọ́gbọ̀n.", "error_text_address": "Àdírẹ́sì àpamọ́wọ́ gbọ́dọ̀ báramu irú owó", "error_text_node_address": "Ẹ jọ̀wọ́ tẹ̀ àdírẹ́sì iPv4", "error_text_node_port": "Ojú ìkànpọ̀ apẹka lè ni nìkan nínú òǹkà l'áàárín òdo àti márùn-úndínlógojí lé ní ẹ̀ẹ́dẹgbẹ̀ta lé ní ọ̀kẹ́ mẹ́ta lé ní ẹ̀ẹ́dẹ́gbàta", "error_text_node_proxy_address": "Jọwọ tẹ :, fun apẹẹrẹ 127.0.0.1:9050", "error_text_payment_id": "Iye ẹyọ ọ̀rọ̀ nínú àmì ìdánimọ̀ àránṣẹ́ gbọ́dọ̀ wà l'áàárín aárùndínlógún dé ẹẹ́rinlélọ́gọ́ta.", "error_text_xmr": "Iye XMR kò lè tóbi ju ìyókù.\nIye díjíìtì léyìn ẹsẹ kò gbọ́dọ̀ tóbi ju eéjìlá.", "error_text_fiat": "Iye àránṣẹ́ kò tóbi ju ìyókù owó.\nIye díjíìtì léyìn ẹsẹ kò gbọ́dọ̀ tóbi ju eéjì.", "error_text_subaddress_name": "Orúkọ àdírẹ́sì tó rẹ̀lẹ̀ kò ni nínú àmì ` , ' \"\nIye ẹyọ ọ̀rọ̀ gbọ́dọ̀ wà láàárín oókan àti ogún", "error_text_amount": "Iye lè ni nìkan nínú àwọn òǹkà", "error_text_wallet_name": "Orúkọ àpamọ́wọ́ lè ni nìkan nínú àwọn òǹkà àti ẹyọ ọ̀rọ̀ àti àmì _ -\nIye ẹyọ ọ̀rọ̀ gbọ́dọ̀ wà láàárín 1 àti 33", "error_text_keys": "Àwọn kọ́kọ́rọ́ àpamọ́wọ́ gbọ́dọ̀ ní ẹyọ ọ̀rọ̀ mẹ́rinlélọ́gọ́ta lílà mẹ́rìndínlógún", "error_text_crypto_currency": "Iye díjíìtì léyìn ẹsẹ kò gbọ́dọ̀ tóbi ju eéjìlá.", "error_text_minimal_limit": "A kò tí ì ṣe pàṣípààrọ̀ tí ${provider} nítorí iye kéré ju ${min} ${currency}", "error_text_maximum_limit": "A kò tí ì ṣe pàṣípààrọ̀ tí ${provider} nítorí iye tóbi ju ${min} ${currency}", "error_text_limits_loading_failed": "A kò tí ì ṣe pàṣípààrọ̀ tí ${provider} nítorí a ti kùnà mú àwọn ààlà wá", "error_text_template": "Orúkọ àwòṣe àti àdírẹ́sì kò lè ni nínú àwọn àmì ` , ' \"\nIye ẹyọ ọ̀rọ̀ náà gbọ́dọ̀ jẹ́ láàárín 1 àti 106", "auth_store_ban_timeout": "ìfòfindè ti gbẹ́mìí mì", "auth_store_banned_for": "A ti fòfin de ẹ̀ nítorí ", "auth_store_banned_minutes": " ìṣéjú", "auth_store_incorrect_password": "Òǹkà ìdánimọ̀ àdáni kọ́ ni èyí", "wallet_store_monero_wallet": "Àpamọ́wọ́ Monero", "wallet_restoration_store_incorrect_seed_length": "Gígùn hóró tí a máa ń lò kọ́ ni èyí", "full_balance": "Ìyókù owó kíkún", "available_balance": "Ìyókù owó tó wà níbẹ̀", "hidden_balance": "Ìyókù owó dídé", "sync_status_syncronizing": "Ń MÚDỌ́GBA", "sync_status_syncronized": "TI MÚDỌ́GBA", "sync_status_not_connected": "KÒ TI DÁRAPỌ̀ MỌ́ Ọ", "sync_status_starting_sync": "Ń BẸ̀RẸ̀ RẸ́", "sync_status_failed_connect": "ÌKÀNPỌ̀ TI KÚ", "sync_status_connecting": "Ń DÁRAPỌ̀ MỌ́", "sync_status_connected": "TI DÁRAPỌ̀ MỌ́", "sync_status_attempting_sync": "Ń GBÌYÀNJÚ MÚDỌ́GBA", "transaction_priority_slow": "Díẹ̀", "transaction_priority_regular": "Àjùmọ̀lò", "transaction_priority_medium": "L’áàárín", "transaction_priority_fast": "Yára", "transaction_priority_fastest": "Yá jù lọ", "trade_for_not_created": "A kò tí ì ṣe pàṣípààrọ̀ ${title}", "trade_not_created": "A kò tí ì ṣe pàṣípààrọ̀ náà", "trade_id_not_found": "Trade ${tradeId} ti a ko ba ri ninu ${title}.", "trade_not_found": "A kò tí ì wá pàṣípààrọ̀.", "trade_state_pending": "Pípẹ́", "trade_state_confirming": "Ń jẹ́rìí", "trade_state_trading": "Ń ṣe pàṣípààrọ̀", "trade_state_traded": "Ti ṣe pàṣípààrọ̀", "trade_state_complete": "Ti ṣetán", "trade_state_to_be_created": "Máa ṣe", "trade_state_unpaid": "Kò tíì san", "trade_state_underpaid": "Ti san iye tó kéré jù", "trade_state_paid_unconfirmed": "Ti san. A kò tíì jẹ́rìí ẹ̀", "trade_state_paid": "Ti san", "trade_state_btc_sent": "Ti san BTC", "trade_state_timeout": "Ti gbẹ́mìí mì", "trade_state_created": "Ti ṣe", "trade_state_finished": "Ti ṣetán", "change_language": "Pààrọ̀ èdè", "change_language_to": "Pààrọ̀ èdè sí ${language}?", "paste": "Fikún ẹ̀dà yín", "restore_from_seed_placeholder": "Ẹ jọ̀wọ́ tẹ̀ hóró yín tàbí fikún ẹ̀dà hóró ḿbí.", "add_new_word": "Fikún ọ̀rọ̀ títun", "incorrect_seed": "Ọ̀rọ̀ tí a tẹ̀ kì í ṣe èyí.", "biometric_auth_reason": "Ya ìka ọwọ́ yín láti ṣe ìfẹ̀rílàdí", "version": "Àtúnse ${currentVersion}", "extracted_address_content": "Ẹ máa máa fi owó ránṣẹ́ sí\n${recipient_name}", "card_address": "Àdírẹ́sì:", "buy": "Rà", "sell": "Tà", "placeholder_transactions": "A máa fihàn àwọn àránṣẹ́ yín ḿbí", "placeholder_contacts": "A máa fihàn àwọn olùbásọ̀rọ̀ yín ḿbí", "template": "Àwòṣe", "confirm_delete_template": "Ìṣe yìí máa yọ àwòṣe yìí kúrò. Ṣé ẹ fẹ́ tẹ̀síwájú?", "confirm_delete_wallet": "Ìṣe yìí máa yọ àpamọ́wọ́ yìí kúrò. Ṣé ẹ fẹ́ tẹ̀síwájú?", "change_wallet_alert_title": "Ẹ pààrọ̀ àpamọ́wọ́ yìí", "change_wallet_alert_content": "Ṣe ẹ fẹ́ pààrọ̀ àpamọ́wọ́ yìí sí ${wallet_name}?", "creating_new_wallet": "Ń dá àpamọ́wọ́ títun", "creating_new_wallet_error": "Àṣìṣe: ${description}", "seed_alert_title": "Ẹ wo", "seed_alert_content": "Hóró ni ọ̀nà nìkan kí ṣẹ̀dà àpamọ́wọ́ yín. Ṣé ẹ ti kọ ọ́ sílẹ̀?", "seed_alert_back": "Padà sọ́dọ̀", "seed_alert_yes": "Mo ti kọ ọ́", "exchange_sync_alert_content": "Ẹ jọ̀wọ́ dúró kí a ti múdọ́gba àpamọ́wọ́ yín", "pre_seed_title": "Ó TI ṢE PÀTÀKÌ", "pre_seed_description": "Ẹ máa wo àwọn ọ̀rọ̀ ${words} lórí ojú tó ń bọ̀. Èyí ni hóró aládàáni yín tó kì í jọra. Ẹ lè fi í nìkan dá àpamọ́wọ́ yín padà sípò tí àṣìṣe tàbí ìbàjẹ́ bá ṣẹlẹ̀. Hóró yín ni ẹ gbọ́dọ̀ kọ sílẹ̀ àti pamọ́ síbí tó kò léwu níta Cake Wallet.", "pre_seed_button_text": "Mo ti gbọ́. O fi hóró mi hàn mi", "provider_error": "Àṣìṣe ${provider}", "use_ssl": "Lo SSL", "trusted": "A ti fọkàn ẹ̀ tán", "color_theme": "Àwọn ààtò àwọ̀", "light_theme": "Funfun bí eérú", "bright_theme": "Funfun", "dark_theme": "Dúdú", "enter_your_note": "Tẹ̀ àkọsílẹ̀ yín", "note_optional": "Àkọsílẹ̀ (ìyàn nìyí)", "note_tap_to_change": "Àkọsílẹ̀ (ẹ tẹ̀ láti pààrọ̀)", "view_in_block_explorer": "Wo lórí olùṣèwádìí àkójọpọ̀", "view_transaction_on": "Wo pàṣípààrọ̀ lórí ", "transaction_key": "Kọ́kọ́rọ́ pàṣípààrọ̀", "confirmations": "Àwọn ẹ̀rí", "recipient_address": "Àdírẹ́sì olùgbà", "extra_id": "Àmì ìdánimọ̀ tó fikún:", "destination_tag": "Orúkọ tí ìbí tó a ránṣẹ́ sí:", "memo": "Àkọsílẹ̀:", "backup": "Ṣẹ̀dà", "change_password": "Pààrọ̀ ọ̀rọ̀ aṣínà", "backup_password": "Ṣẹ̀dà ọ̀rọ̀ aṣínà", "write_down_backup_password": "Ẹ jọ̀wọ́ ẹ̀dà ọ̀rọ̀ aṣínà ti ẹ̀dà nípamọ́ yín tó máa ń bá yín ṣí àkọsílẹ̀ yín l'ẹ kọ sílẹ̀.", "export_backup": "Sún ẹ̀dà nípamọ́ síta", "save_backup_password": "Ẹ jọ̀wọ́ dájú pé ẹ ti pamọ́ ọ̀rọ̀ aṣínà ti ẹ̀dà nípamọ́ yín. Ti ẹ kò bá ni í, ẹ kò lè ṣí àwọn àkọsílẹ̀ nípamọ́ yín.", "backup_file": "Ṣẹ̀dà akọsílẹ̀", "edit_backup_password": "Pààrọ̀ ọ̀rọ̀ aṣínà", "save_backup_password_alert": "Pamọ́ ọ̀rọ̀ aṣínà ti ẹ̀dà", "change_backup_password_alert": "Ẹ kò lè fi ọ̀rọ̀ aṣínà títun ti ẹ̀dà nípamọ́ ṣí àwọn àkọsílẹ̀ nípamọ́ tẹ́lẹ̀tẹ́lẹ̀ yín. Ẹ máa fi ọ̀rọ̀ aṣínà ti ẹ̀dà nípamọ́ títun ṣí àwọn àkọsílẹ̀ nípamọ́ títun nìkan. Ṣé ó dá ẹ lójú pé ẹ fẹ́ pààrọ̀ aṣínà ti ẹ̀dà nípamọ́?", "enter_backup_password": "Tẹ̀ ọ̀rọ̀ aṣínà ti ẹ̀dà ḿbí", "select_backup_file": "Select backup file", "import": "Gba wọlé", "please_select_backup_file": "Ẹ jọ̀wọ́ yan àkọsílẹ̀ nípamọ́ àti tẹ̀ ọ̀rọ̀ aṣínà ti ẹ̀dà.", "fixed_rate": "Iye t'á ṣẹ́ owó sí ò ní pààrọ̀", "fixed_rate_alert": "Ẹ lè tẹ̀ iye owó tó ń bọ̀ tí iye t'a ṣẹ́ owó sí bá is checked. Ṣé ẹ fẹ́ sún ipò ti iye t'á ṣẹ́ owó sí ò ní pààrọ̀ mọ́?", "xlm_extra_info": "Ẹ jọ̀wọ́ ẹ kò gbàgbé pèsè àmì ìdánimọ̀ àkọsílẹ̀ t'ẹ́ ń bá ránṣẹ́ pàṣípààrọ̀ ti XLM yín sí ilé ìfowóṣòwò", "xrp_extra_info": "Ẹ jọ̀wọ́ ẹ kò gbàgbé pèsè orúkọ̀ àdírẹ́sì ti a ránṣẹ́ sí t'ẹ́ bá ránṣẹ pàṣípààrọ̀ ti XRP yín sílé ìfowóṣòwò", "exchange_incorrect_current_wallet_for_xmr": "T'ẹ́ bá fẹ́ pàṣípààrọ̀ XMR láti ìyókù owó Cake Wallet yín, ẹ jọ̀wọ́ kọ́kọ́ sún àpamọ́wọ́ Monero mọ́.", "confirmed": "A ti jẹ́rìí ẹ̀", "unconfirmed": "A kò tí ì jẹ́rìí ẹ̀", "displayable": "A lè ṣàfihàn ẹ̀", "submit_request": "Ṣé ìbéèrè", "buy_alert_content": "Lọwọlọwọ a ṣe atilẹyin rira Bitcoin, Ethereum, Litecoin, ati Monero. Jọwọ ṣẹda tabi yipada si Bitcoin, Ethereum, Litecoin, tabi apamọwọ Monero.", "sell_alert_content": "Lọwọlọwọ a ṣe atilẹyin tita Bitcoin, Ethereum ati Litecoin nikan. Jọwọ ṣẹda tabi yipada si Bitcoin, Ethereum tabi apamọwọ Litecoin rẹ.", "outdated_electrum_wallet_description": "Àwọn àpamọ́wọ́ títun Bitcoin ti a ti dá nínú Cake Wallet lọ́wọ́lọ́wọ́. Àwọn àpamọ́wọ́ títun t'á dá nínú Cake Wallet ni hóró tó ní ọ̀rọ̀ mẹ́rinlélógún. Ẹ gbọ́dọ̀ dá àpamọ́wọ́. Ẹ sì sún gbogbo owó yín sí àpamọ́wọ́ títun náà tó dá lórí ọ̀rọ̀ mẹ́rinlélógún. Ẹ sì gbọ́dọ̀ yé lo àwọn àpamọ́wọ́ tó dá lórí hóró tó ní ọ̀rọ̀ méjìlá. Ẹ jọ̀wọ́ ṣe èyí láìpẹ́ kí ẹ ba owó yín.", "understand": "Ó ye mi", "apk_update": "Àtúnse áàpù títun wà", "buy_bitcoin": "Ra Bitcoin", "buy_with": "Rà pẹ̀lú", "moonpay_alert_text": "Iye owó kò gbọ́dọ̀ kéré ju ${minAmount} ${fiatCurrency}", "outdated_electrum_wallet_receive_warning": "Ẹ KÒ FI BITCOIN SÍ ÀPAMỌ́WỌ́ YÌÍ t'á ti dá a nínú Cake Wallet àti àpamọ́wọ́ yìí ni hóró ti ọ̀rọ̀ méjìlá. A lè pàdánù BTC t'á ránṣẹ́ sí àpamọ́wọ́ yìí. Ẹ dá àpamọ́wọ́ títun tó ni hóró tó ni ọ̀rọ̀ mẹ́rinlélógún (Ẹ tẹ àkọsílẹ̀ tó wa l’ókè l'ọ́tún nígbàna, ẹ sì yan àwọn àpamọ́wọ́ nígbàna, ẹ sì yan Dá Àpamọ́wọ́ Títun nígbàna, ẹ sì yan Bitcoin) àti sún Bitcoin yín síbẹ̀ ní sinsìn yẹn. Àwọn àpamọ́wọ́ títun (hóró ni ọ̀rọ̀ mẹ́rinlélógún) láti Cake Wallet wa láìléwu.", "do_not_show_me": "Kò fi eléyìí hàn mi mọ́", "unspent_coins_title": "Àwọn owó ẹyọ t'á kò tí ì san", "unspent_coins_details_title": "Àwọn owó ẹyọ t'á kò tí ì san", "freeze": "Tì pa", "frozen": "Ó l'a tì pa", "coin_control": "Ìdarí owó ẹyọ (ìyàn nìyí)", "address_detected": "A ti gbọ́ àdírẹ́sì", "address_from_domain": "Àdírẹ́sì yìí wá láti ${domain} lórí Unstoppable Domains", "add_receiver": "Fikún àdírẹ́sì mìíràn (ìyàn nìyí)", "manage_yats": "Bójú Yats", "yat_alert_title": "Lílò Yat láti ránṣẹ́ àti gba owó dùn ṣe pọ̀ ju lọ", "yat_alert_content": "Àwọn olùṣàmúlò ti Cake Wallet lè fi orúkọ olùṣàmúlò t'á dá lórí emójì tó kì í jọra ránṣẹ́ àti gba gbogbo àwọn irú owó tíwọn yàn láàyò lọ́wọ́lọ́wọ́.", "get_your_yat": "Gba Yat yín", "connect_an_existing_yat": "So Yat wíwà", "connect_yats": "So àwọn Yat", "yat_address": "Àdírẹ́sì Yat", "yat": "Yat", "address_from_yat": "Àdírẹ́sì yìí wá láti ${emoji} lórí Yat", "yat_error": "Àṣìṣe Yat", "yat_error_content": "Kò sí àdírẹ́sìkádírẹ́sì tó so Yat yìí. Ẹ gbìyànjú Yat mìíràn", "choose_address": "\n\nẸ jọ̀wọ́ yan àdírẹ́sì:", "yat_popup_title": "Ẹ lè dá àpamọ́wọ́ yín láti emójì.", "yat_popup_content": "Ẹ lè fi Yat yín (orúkọ olùṣàmúlò kúkurú t'á dá lórí emójì) ránṣẹ́ àti gba owó nínú Cake Wallet lọ́wọ́lọ́wọ́. Bójú Yats lórí ojú ààtò lígbàkúgbà.", "second_intro_title": "Àdírẹ́sì kan t'á dá láti emójì tó pàṣẹ gbogbo ohun wà", "second_intro_content": "Àdírẹ́sì kan tó dá lórí emójì tó kì í jọra ni Yat yín. Ó rọ́pò gbogbo àwọn àdírẹ́sì gígùn yín tó dá lórí ìlà mẹ́rìndínlógún ti gbogbo àwọn iye owó yín.", "third_intro_title": "Àlàáfíà ni Yat àti àwọn ìmíìn jọ wà", "third_intro_content": "A sì lè lo Yats níta Cake Wallet. A lè rọ́pò Àdírẹ́sì kankan àpamọ́wọ́ fún Yat!", "learn_more": "Túbọ̀ kọ́", "search": "Wá", "search_language": "Wá èdè", "search_currency": "Wá irú owó", "new_template": "Àwòṣe títun", "electrum_address_disclaimer": "A dá àwọn àdírẹ́sì títun ní gbogbo àwọn ìgbà t'ẹ́ lo ó kan ṣùgbọ́n ẹ lè tẹ̀síwájú lo àwọn àdírẹ́sì tẹ́lẹ̀tẹ́lẹ̀.", "wallet_name_exists": "Ẹ ti ní àpamọ́wọ́ pẹ̀lú orúkọ̀ yẹn. Ẹ jọ̀wọ́ yàn orúkọ̀ tó yàtọ̀ tàbí pààrọ̀ orúkọ ti àpamọ́wọ́ tẹ́lẹ̀.", "market_place": "Ọjà", "cake_pay_title": "Àwọn káàdì ìrajà t'á lò nínú ìtajà kan ti Cake Pay", "cake_pay_subtitle": "Ra àwọn káàdì ìrajà t'á lò nínú ìtajà kan fún owó tí kò pọ̀ (USA nìkan)", "cake_pay_web_cards_title": "Àwọn káàdì wẹ́ẹ̀bù ti Cake Pay", "cake_pay_web_cards_subtitle": "Ra àwọn káàdì ìrajà t'á lò nínú ìtajà kan àti àwọn káàdì náà t'á lè lò níbikíbi", "about_cake_pay": "Cake Pay jẹ́ kí ẹ lè fi owó wẹ́ẹ̀bù ra àwọn káàdì ìrajà t'á lò nínú iye ìtajà kan. Ẹ lè san wọn láìpẹ́ nítajà 150,000 nínú Amẹ́ríkà.", "cake_pay_account_note": "Ẹ fi àdírẹ́sì ímeèlì nìkan forúkọ sílẹ̀ k'ẹ́ rí àti ra àwọn káàdì. Ẹ lè fi owó tó kéré jù ra àwọn káàdì kan!", "already_have_account": "Ṣé ẹ ti ní àkáǹtì?", "create_account": "Dá àkáǹtì", "privacy_policy": "Òfin Aládàáni", "welcome_to_cakepay": "Ẹ káàbọ̀ sí Cake Pay!", "sign_up": "Forúkọ sílẹ̀", "forgot_password": "Ẹ ti gbàgbé ọ̀rọ̀ aṣínà", "reset_password": "Tún ọ̀rọ̀ aṣínà ṣe", "gift_cards": "Àwọn káàdì ìrajà t'á lò nínú iye kan ìtajà", "setup_your_debit_card": "Dá àwọn káàdì ìrajà yín", "no_id_required": "Ẹ kò nílò àmì ìdánimọ̀. Ẹ lè fikún owó àti san níbikíbi", "how_to_use_card": "Báyìí ni wọ́n ṣe ń lo káàdì yìí.", "purchase_gift_card": "Ra káàdì ìrajà t'á lò nínú irú kan ìtajà", "verification": "Ìjẹ́rìísí", "fill_code": "Ẹ jọ̀wọ́ tẹ̀ ọ̀rọ̀ ìjẹ́rìísí t'á ti ránṣẹ́ sí ímeèlì yín.", "dont_get_code": "Ṣé ẹ ti gba ọ̀rọ̀ ìdánimọ̀?", "resend_code": "Ẹ jọ̀wọ́ tún un ránṣé", "debit_card": "Káàdì ìrajà", "cakepay_prepaid_card": "Káàdì ìrajà ti CakePay", "no_id_needed": "Ẹ kò nílò àmì ìdánimọ̀!", "frequently_asked_questions": "Àwọn ìbéèrè la máa ń béèrè", "debit_card_terms": "Òfin ti olùṣe àjọrò káàdì ìrajà bójú irú ọ̀nà t'á pamọ́ àti a lo òǹkà ti káàdì ìrajà yín (àti ọ̀rọ̀ ìdánimọ̀ tí káàdì náà) nínú àpamọ́wọ́ yìí.", "please_reference_document": "Ẹ jọ̀wọ́ fi àwọn àkọsílẹ̀ l’ábẹ́ túbọ̀ mọ ìsọfúnni.", "cardholder_agreement": "Àjọrò olùṣe káàdì ìrajà", "e_sign_consent": "Jẹ́rìí sí lórí ayélujára", "agree_and_continue": "Jọ Rò àti Tẹ̀síwájú", "email_address": "Àdírẹ́sì ímeèlì", "agree_to": "Tẹ́ ẹ bá dá àkáǹtì ẹ jọ rò ", "and": "àti", "enter_code": "Tẹ̀ ọ̀rọ̀", "congratulations": "Ẹ kúuṣẹ́ ooo!", "you_now_have_debit_card": "Ẹ ni káàdì ìrajà lọ́wọ́lọ́wọ́", "min_amount": "kò kéré ju: ${value}", "max_amount": "kò tóbi ju: ${value}", "enter_amount": "Tẹ̀ iye", "billing_address_info": "Tí ọlọ́jà bá bèèrè àdírẹ́sì sísan yín, fún òun ni àdírẹ́sì t'á ránṣẹ́ káàdì yìí sí", "order_physical_card": "Bèèrè káàdì t'ara", "add_value": "Fikún owó", "activate": "Fi àyè gba", "get_a": "Gba ", "digital_and_physical_card": " káàdì ìrajà t'ara àti ti ayélujára", "get_card_note": " t'ẹ lè fikún owó ayélujára. Ẹ kò nílò ìṣofúnni àfikún!", "signup_for_card_accept_terms": "Ẹ f'orúkọ sílẹ̀ láti gba káàdì àti àjọrò.", "add_fund_to_card": "Ẹ fikún owó sí àwọn káàdì (kò tóbi ju ${value})", "use_card_info_two": "A pààrọ̀ owó sí owó Amẹ́ríkà tó bá wà nínú àkanti t'á ti fikún tẹ́lẹ̀tẹ́lẹ̀. A kò kó owó náà nínú owó ayélujára.", "use_card_info_three": "Ẹ lo káàdí ayélujára lórí wẹ́ẹ̀bù tàbí ẹ lò ó lórí àwọn ẹ̀rọ̀ ìrajà tíwọn kò kò.", "optionally_order_card": "Ẹ lè fi ìyàn bèèrè káàdì t'ara.", "hide_details": "Dé ìsọfúnni kékeré", "show_details": "Fi ìsọfúnni kékeré hàn", "upto": "kò tóbi ju ${value}", "discount": "Pamọ́ ${value}%", "gift_card_amount": "owó ìyókù káàdì", "bill_amount": "Iye ìwé owó", "you_pay": "Ẹ sàn", "tip": "Owó àfikún:", "custom": "Ohun t'á ti pààrọ̀", "by_cake_pay": "láti ọwọ́ Cake Pay", "expires": "Ó parí", "mm": "Os", "yy": "Ọd", "online": "Lórí ayélujára", "offline": "kò wà lórí ayélujára", "gift_card_number": "Òǹkà káàdì ìrajì", "pin_number": "Òǹkà ìdánimọ̀ àdáni", "total_saving": "Owó t'ẹ́ ti pamọ́", "last_30_days": "Ọ̀jọ̀ mọ́gbọ̀n tó kọjà", "avg_savings": "Ìpamọ́ l’óòrèkóòrè", "view_all": "Wo gbogbo nǹkan kan", "active_cards": "Àwọn káàdì títàn", "delete_account": "Pa ìṣàmúlò", "cards": "Àwọn káàdì", "active": "Ó títàn", "redeemed": "Ó lílò", "gift_card_balance_note": "Àwọn káàdì ìrajà t'á lò nínú irú kan ìtajà tíwọn ṣì ní owó máa fihàn ḿbí", "gift_card_redeemed_note": "Àwọn káàdì ìrajà t'á lò nínú irú kan ìtajà t'ẹ́ ti lò máa fihàn ḿbí", "logout": "Jáde", "add_tip": "Fún owó àfikún", "percentageOf": "láti ${amount}", "is_percentage": "jẹ́", "search_category": "Wá nínú ẹgbẹ́", "mark_as_redeemed": "Fún orúkọ lílò", "more_options": "Ìyàn àfikún", "awaiting_payment_confirmation": "À ń dúró de ìjẹ́rìísí àránṣẹ́", "transaction_sent_notice": "Tí aṣàfihàn kò bá tẹ̀síwájú l'áàárín ìṣẹ́jú kan, ẹ tọ́ olùṣèwádìí àkójọpọ̀ àti ímeèlì yín wò.", "agree": "Jọ rò", "in_store": "A níyí", "generating_gift_card": "À ń dá káàdì ìrajà t'á lò nínú irú kan ìtajà", "payment_was_received": "Àránṣẹ́ yín ti dé.", "proceed_after_one_minute": "Tí aṣàfihàn kò bá tẹ̀síwájú l'áàárín ìṣẹ́jú kan, ẹ tọ́ ímeèlì yín wò.", "order_id": "Àmì ìdánimọ̀ ti ìbéèrè", "gift_card_is_generated": "A ti dá káàdí ìrajà t'á lò nínú irú kan ìtajà", "open_gift_card": "Ṣí káàdí ìrajà t'á lò nínú irú kan ìtajà", "contact_support": "Bá ìranlọ́wọ́ sọ̀rọ̀", "gift_cards_unavailable": "A lè fi Monero, Bitcoin, àti Litecoin nìkan ra káàdí ìrajà t'á lò nínú irú kan ìtajà lọ́wọ́lọ́wọ́", "introducing_cake_pay": "Ẹ bá Cake Pay!", "cake_pay_learn_more": "Láìpẹ́ ra àti lo àwọn káàdí ìrajà t'á lò nínú irú kan ìtajà nínú áàpù!\nẸ tẹ̀ òsì de ọ̀tún láti kọ́ jù.", "automatic": "Ó máa ń ṣàdédé", "fixed_pair_not_supported": "A kì í ṣe k'á fi àwọn ilé pàṣípààrọ̀ yìí ṣe pàṣípààrọ̀ irú owó méji yìí", "variable_pair_not_supported": "A kì í ṣe k'á fi àwọn ilé pàṣípààrọ̀ yìí ṣe pàṣípààrọ̀ irú owó méji yìí", "none_of_selected_providers_can_exchange": "Àwọn ilé pàṣípààrọ̀ yíyàn kò lè ṣe pàṣípààrọ̀ yìí", "choose_one": "Ẹ yàn kan", "choose_from_available_options": "Ẹ yàn láti àwọn ìyàn yìí:", "custom_redeem_amount": "Iye owó l'á máa ná", "add_custom_redemption": "Tẹ̀ iye owó t'ẹ́ fẹ́ ná", "remaining": "ìyókù", "delete_wallet": "Pa àpamọ́wọ́", "delete_wallet_confirm_message": "Ṣó dá ẹ lójú pé ẹ fẹ́ pa àpamọ́wọ́ ${wallet_name}?", "low_fee": "Owó àfikún kékeré", "low_fee_alert": "Ẹ ń fi owó àfikún kékeré fún àwọn àránṣẹ́ yín lágbára. Eleyìí lè pẹ́ gba àránṣẹ́ yín. Ó sì lè dá àwọn iye mìíràn t'á ṣẹ́ owó sí. Ó sì lè pa àwọn pàṣípààrọ̀. A dábàá pé k'ẹ́ lo owó àfikún títobi láti ṣe àṣejèrè.", "ignor": "Ṣàìfiyèsí", "use_suggested": "Lo àbá", "do_not_share_warning_text": "Ẹ kò pín wọnyìí sí ẹnikẹ́ni. Ẹ sì kò pin wọnyìí sí ìranlọ́wọ́. Ẹnikẹ́ni lè jí owó yín! Wọ́n máa jí owó yín!", "help": "ìranlọ́wọ́", "all_transactions": "Gbogbo àwọn àránṣẹ́", "all_trades": "Gbogbo àwọn pàṣípààrọ̀", "connection_sync": "Ìkànpọ̀ àti ìbádọ́gba", "security_and_backup": "Ìṣọ́ àti ẹ̀dà nípamọ́", "create_backup": "Ṣẹ̀dà nípamọ́", "privacy_settings": "Ààtò àdáni", "privacy": "Ìdáwà", "display_settings": "Fihàn àwọn ààtò", "other_settings": "Àwọn ààtò mìíràn", "require_pin_after": "Ẹ nílò òǹkà ìdánimọ̀ àdáni láàárín", "always": "Ní gbogbo àwọn ìgbà", "minutes_to_pin_code": "${minute} ìṣẹ́jú", "disable_exchange": "Pa ilé pàṣípààrọ̀", "advanced_privacy_settings": "Àwọn ààtò àdáni títóbi", "settings_can_be_changed_later": "Ẹ lè pààrọ̀ àwọn ààtò yìí nínú ààtò áàpù t’ó bá yá", "add_custom_node": "Fikún apẹka títun t'ẹ́ pààrọ̀", "disable_fiat": "Pa owó tí ìjọba pàṣẹ wa lò", "fiat_api": "Ojú ètò áàpù owó tí ìjọba pàṣẹ wa lò", "disabled": "Wọ́n tí a ti pa", "enabled": "Wọ́n tíwọn ti tan", "tor_only": "Tor nìkan", "unmatched_currencies": "Irú owó ti àpamọ́wọ́ yín kì í ṣe irú ti yíya àmì ìlujá", "contact_list_contacts": "Àwọn olùbásọ̀rọ̀", "contact_list_wallets": "Àwọn àpamọ́wọ́ mi", "bitcoin_payments_require_1_confirmation": "Àwọn àránṣẹ́ Bitcoin nílò ìjẹ́rìísí kan. Ó lè lo ìṣéjú ogun tàbí ìṣéjú jù. A dúpẹ́ fún sùúrù yín! Ẹ máa gba ímeèlì t'ó bá jẹ́rìísí àránṣẹ́ náà.", "send_to_this_address": "Ẹ fi ${currency} ${tag}ránṣẹ́ sí àdírẹ́sì yìí", "arrive_in_this_address": "${currency} ${tag} máa dé sí àdírẹ́sì yìí", "do_not_send": "Ẹ kò ránṣ", "error_dialog_content": "Àṣìṣe ti dé.\n\nẸ jọ̀wọ́, fi àkọsílẹ̀ àṣìṣe ránṣẹ́ sí ẹgbẹ́ ìranlọ́wọ́ wa kí áàpù wa bá túbọ̀ dára.", "cold_or_recover_wallet": "Fi owo aisan tabi yiyewo owo iwe iwe", "please_wait": "Jọwọ saa", "sweeping_wallet": "Fi owo iwe iwe wofo", "sweeping_wallet_alert": "Yio kọja pada si ikan yii. Kì yoo daadaa leede yii tabi owo ti o ti fi se iwe iwe naa yoo gbe.", "invoice_details": "Iru awọn ẹya ọrọ", "donation_link_details": "Iru awọn ẹya ọrọ ti o funni", "anonpay_description": "Ṣe akọkọ ${type}. Awọn alabara le ${method} pẹlu eyikeyi iwo ise ati owo yoo wọle si iwe iwe yii.", "create_invoice": "Ṣe iwe iwe", "create_donation_link": "Ṣe kọọkan alabara asopọ", "optional_email_hint": "Ṣeto imọ-ẹrọ iye fun owo ti o gbọdọjọ", "optional_description": "Ṣeto ẹru iye", "optional_name": "Ṣeto orukọ ti o ni", "clearnet_link": "Kọja ilọ oke", "onion_link": "Kọja ilọ alubosa", "decimal_places_error": "Oọ̀rọ̀ ayipada ti o wa ni o dara julọ", "edit_node": "Tun awọn ọwọnrin ṣiṣe", "frozen_balance": "Aferugbo Iye", "settings": "Awọn aseṣe", "sell_monero_com_alert_content": "Kọ ju lọwọ Monero ko ṣe ni ibamu", "error_text_input_below_minimum_limit": "Iye jọwọ ni o kere ti o wọle diẹ", "error_text_input_above_maximum_limit": "Iye jọwọ ni o yẹ diẹ ti o wọle diẹ", "show_market_place": "Wa Sopọ Pataki", "prevent_screenshots": "Pese asapọ ti awọn ẹrọ eto aṣa", "profile": "profaili", "close": "sunmo", "modify_2fa": "Fi iṣiro 2FA sii Cake", "disable_cake_2fa": "Ko 2FA Cake sii", "question_to_disable_2fa": "Ṣe o wa daadaa pe o fẹ ko 2FA Cake? Ko si itumọ ti a yoo nilo lati ranse si iwe iwe naa ati eyikeyi iṣẹ ti o ni.", "disable": "Ko si", "setup_2fa": "Ṣeto Cake 2FA", "verify_with_2fa": "Ṣeẹda pẹlu Cake 2FA", "totp_code": "Koodu TOTP", "please_fill_totp": "Jọwọ bọ ti ẹrọ ti o wọle ni 8-digits ti o wa ni eto miiran re", "totp_2fa_success": "Pelu ogo! Cake 2FA ti fi sii lori iwe iwe yii. Tọ, mọ iye ẹrọ miiran akojọrọ jẹki o kọ ipin eto.", "totp_verification_success": "Ìbẹrẹ dọkita!", "totp_2fa_failure": "Koodu ti o daju ko ri. Jọwọ jẹ koodu miiran tabi ṣiṣẹ iwe kiakia. Lo fun 2FA eto ti o ba ṣe ni jẹ 2FA ti o gba idaniloju 8-digits ati SHA512.", "enter_totp_code": "Jọwọ pọ koodu TOTP.", "add_secret_code": "Fọya koodu iye yii si eto miiran", "totp_secret_code": "Koodu iye TOTP", "important_note": "Iwọ nikan nipasẹ iwe iṣẹ kan", "setup_2fa_text": "Cake 2FA kii ṣe nipasẹ aisan tabi ni akoso aisan. 2FA ti ṣe pada ninu awọn iṣẹ pataki, bi atilẹyin ti o fun iṣẹ rẹ ti o ti jẹ saanu.\n\n Cake 2FA kii ṣe pada ninu atilẹyin ti o ti ba alabara kan ti o sise gidi gan.\n\n Ti o ba pọ akosile rẹ 2FA, O YOO RI ATOJU SI IWE IWE NA. O yoo nilo lati yan pẹlu iwe iwe ni o ba ṣe iṣẹ rẹ. O ni aṣẹ iru ki o gba asise akojọ iwe iwe rẹ! Nitori a ko ni aṣẹ pẹlu ohun ti o ba ṣe iṣẹ rẹ lati yan pẹlu akojọ iwe iwe rẹ, nitori Cake ni iwe iwe ti ko se iṣẹ itumọ.", "setup_totp_recommended": "Sọ TOTP (Kẹṣọdọ)", "disable_buy": "Ko iṣọrọ ọja", "disable_sell": "Ko iṣọrọ iṣọrọ", "cake_2fa_preset": "Cake 2FA Tito", "narrow": "Taara", "normal": "Deede", "aggressive": "Onítara", "require_for_assessing_wallet": "Beere fun wiwọle si apamọwọ", "require_for_sends_to_non_contacts": "Beere fun fifiranṣẹ si awọn ti kii ṣe awọn olubasọrọ", "require_for_sends_to_contacts": "Beere fun fifiranṣẹ si awọn olubasọrọ", "require_for_sends_to_internal_wallets": "Beere fun fifiranṣẹ si awọn apamọwọ inu", "require_for_exchanges_to_internal_wallets": "Beere fun awọn paṣipaarọ si awọn apamọwọ inu", "require_for_adding_contacts": "Beere fun fifi awọn olubasọrọ kun", "require_for_creating_new_wallets": "Beere fun ṣiṣẹda titun Woleti", "require_for_all_security_and_backup_settings": "Beere fun gbogbo aabo ati awọn eto afẹyinti", "available_balance_description": "“Iwọntunwọnsi Wa” tabi “Iwọntunwọnsi Ijẹrisi” jẹ awọn owo ti o le ṣee lo lẹsẹkẹsẹ. Ti awọn owo ba han ni iwọntunwọnsi kekere ṣugbọn kii ṣe iwọntunwọnsi oke, lẹhinna o gbọdọ duro iṣẹju diẹ fun awọn owo ti nwọle lati gba awọn ijẹrisi nẹtiwọọki diẹ sii. Lẹhin ti wọn gba awọn ijẹrisi diẹ sii, wọn yoo jẹ inawo.", "syncing_wallet_alert_title": "Apamọwọ rẹ n muṣiṣẹpọ", "syncing_wallet_alert_content": "Iwontunws.funfun rẹ ati atokọ idunadura le ma pari titi ti yoo fi sọ “SYNCHRONIZED” ni oke. Tẹ/tẹ ni kia kia lati ni imọ siwaju sii.", "home_screen_settings": "Awọn eto iboju ile", "sort_by": "Sa pelu", "search_add_token": "Wa / Fi àmi kun", "edit_token": "Ṣatunkọ àmi", "warning": "Ikilo", "add_token_warning": "Ma ṣe ṣatunkọ tabi ṣafikun awọn ami bi a ti fun ni aṣẹ nipasẹ awọn scammers.\nNigbagbogbo jẹrisi awọn adirẹsi ami pẹlu awọn orisun olokiki!", "add_token_disclaimer_check": "Mo ti jẹrisi adirẹsi adehun ami ati alaye nipa lilo orisun olokiki kan. Fifi irira tabi alaye ti ko tọ le ja si isonu ti owo.", "token_contract_address": "Àmi guide adirẹsi", "token_name": "Orukọ àmi fun apẹẹrẹ: Tether", "token_symbol": "Aami aami fun apẹẹrẹ: USDT", "token_decimal": "Àmi eleemewa", "field_required": "E ni lati se nkan si aye yi", "pin_at_top": "pin ${tokini} ni oke", "invalid_input": "Iṣawọle ti ko tọ", "fiat_balance": "Fiat Iwontunws.funfun", "gross_balance": "Iwontunws.funfun apapọ", "alphabetical": "Labidibi", "generate_name": "Ṣẹda Orukọ", "balance_page": "Oju-iwe iwọntunwọnsi", "share": "Pinpin", "slidable": "Slidable", "manage_nodes": "Ṣakoso awọn apa", "etherscan_history": "Etherscan itan", "template_name": "Orukọ Awoṣe", "change_rep": "Yi Aṣoju", "change_rep_message": "Ṣe o da ọ loju pe o fẹ yi awọn aṣoju pada?", "unsupported_asset": "A ko ṣe atilẹyin iṣẹ yii fun dukia yii. Jọwọ ṣẹda tabi yipada si apamọwọ iru dukia atilẹyin.", "manage_pow_nodes": "Ṣakoso awọn Nodes PoW", "support_title_live_chat": "Atilẹyin ifiwe", "support_description_live_chat": "Free ati sare! Ti oṣiṣẹ awọn aṣoju wa lati ṣe iranlọwọ", "support_title_guides": "Akara oyinbo Awọn Itọsọna Awọki oyinbo", "support_description_guides": "Iwe ati atilẹyin fun awọn ọran ti o wọpọ", "support_title_other_links": "Awọn ọna asopọ atilẹyin miiran", "support_description_other_links": "Darapọ mọ awọn agbegbe wa tabi de wa awọn alabaṣepọ wa nipasẹ awọn ọna miiran", "choose_derivation": "Yan awọn apamọwọ apamọwọ", "new_first_wallet_text": "Ni rọọrun jẹ ki o jẹ ki o jẹ ki o jẹ ki a mu", "monero_dark_theme": "Monero Dudu Akori", "bitcoin_dark_theme": "Bitcoin Dark Akori", "bitcoin_light_theme": "Bitcoin Light Akori", "high_contrast_theme": "Akori Iyatọ giga", "matrix_green_dark_theme": "Matrix Green Dark Akori", "monero_light_theme": "Monero Light Akori", "select_destination": "Jọwọ yan ibi ti o nlo fun faili afẹyinti.", "auto_generate_subaddresses": "Aṣiṣe Ibi-Afọwọkọ", "save_to_downloads": "Fipamọ si Awọn igbasilẹ", "invalid_password": "Ọrọ igbaniwọle ti ko wulo", "unlock": "Sisalẹ", "enter_wallet_password": "Tẹ ọrọ igbaniwọle apamọwọ", "repeat_wallet_password": "Tun ọrọ igbaniwọle apamọwọ naa", "wallet_password_is_empty": "Ọrọ igbaniwọle apamọwọ ti ṣofo. Ọrọ igbaniwọle apamọwọ ko yẹ ki o ṣofo", "repeated_password_is_incorrect": "Ọrọ igbaniwọle tun jẹ aṣiṣe. Jọwọ tun ọrọigbaniwọle apamọwọ lẹẹkansi.", "select_buy_provider_notice": "Yan olupese Ra loke. O le skii iboju yii nipa ṣiṣeto olupese rẹ ni awọn eto App.", "onramper_option_description": "Ni kiakia Ra Crypto pẹlu ọpọlọpọ awọn ọna isanwo. Wa ni ọpọlọpọ awọn orilẹ-ede. Itankale ati awọn idiyele yatọ.", "default_buy_provider": "Aiyipada Ra Olupese", "ask_each_time": "Beere lọwọ kọọkan", "buy_provider_unavailable": "Olupese lọwọlọwọ ko si.", "signTransaction": "Wole Idunadura", "errorGettingCredentials": "Kuna: Aṣiṣe lakoko gbigba awọn iwe-ẹri", "errorSigningTransaction": "Aṣiṣe kan ti waye lakoko ti o fowo si iṣowo", "pairingInvalidEvent": "Pipọpọ Iṣẹlẹ Ti ko tọ", "chains": "Awọn ẹwọn", "methods": "Awọn ọna", "events": "Awọn iṣẹlẹ", "reject": "Kọ", "approve": "Fi ọwọ si", "expiresOn": "Ipari lori", "walletConnect": "Asopọmọra apamọwọ", "nullURIError": "URI jẹ asan", "connectWalletPrompt": "So apamọwọ rẹ pọ pẹlu WalletConnect lati ṣe awọn iṣowo", "newConnection": "Tuntun Asopọ", "activeConnectionsPrompt": "Awọn asopọ ti nṣiṣe lọwọ yoo han nibi", "deleteConnectionConfirmationPrompt": "Ṣe o da ọ loju pe o fẹ paarẹ asopọ si", "event": "Iṣẹlẹ", "successful": "Aseyori", "wouoldLikeToConnect": "yoo fẹ lati sopọ", "message": "Ifiranṣẹ", "do_not_have_enough_gas_asset": "O ko ni to ${currency} lati ṣe idunadura kan pẹlu awọn ipo nẹtiwọki blockchain lọwọlọwọ. O nilo diẹ sii ${currency} lati san awọn owo nẹtiwọọki blockchain, paapaa ti o ba nfi dukia miiran ranṣẹ.", "totp_auth_url": "TOTP AUTH URL", "awaitDAppProcessing": "Fi inurere duro fun dApp lati pari sisẹ.", "copyWalletConnectLink": "Daakọ ọna asopọ WalletConnect lati dApp ki o si lẹẹmọ nibi", "enterWalletConnectURI": "Tẹ WalletConnect URI sii", "seed_key": "Bọtini Ose", "enter_seed_phrase": "Tẹ ọrọ-iru irugbin rẹ", "add_contact": "Fi olubasọrọ kun", "exchange_provider_unsupported": "${providerName} ko ni atilẹyin mọ!", "domain_looks_up": "Awọn wiwa agbegbe", "require_for_exchanges_to_external_wallets": "Beere fun awọn paṣipaarọ si awọn apamọwọ ita", "camera_permission_is_required": "A nilo igbanilaaye kamẹra.\nJọwọ jeki o lati app eto.", "switchToETHWallet": "Jọwọ yipada si apamọwọ Ethereum ki o tun gbiyanju lẹẹkansi" }