{
    "welcome" : "Ẹ káàbọ sí",
    "cake_wallet" : "Cake Wallet",
    "first_wallet_text" : "Àpamọ́wọ́ t'á fi Monero, Bitcoin, Litecoin, àti Haven pamọ́ wà pa",
    "please_make_selection" : "Ẹ jọ̀wọ́, yàn dá àpamọ́wọ́ yín tàbí dá àpamọ́wọ́ yín padà n’ísàlẹ̀.",
    "create_new" : "Dá àpamọ́wọ́ tuntun",
    "restore_wallet" : "Mú àpamọ́wọ́ padà",

    "monero_com": "Monero.com latí ọwọ́ Cake Wallet",
    "monero_com_wallet_text": "Àpamọ́wọ́ Monero wà pa",

    "haven_app": "Haven latí ọwọ́ Cake Wallet",
    "haven_app_wallet_text": "Àpamọ́wọ́ Haven wà pa",

    "accounts" : "Àwọn àkáǹtì",
    "edit" : "Pààrọ̀",
    "account" : "Àkáǹtì",
    "add" : "Fikún",


    "address_book" : "Ìwé Àdírẹ́sì",
    "contact" : "Olùbásọ̀rọ̀",
    "please_select" : "Ẹ jọ̀wọ́ yàn:",
    "cancel" : "Fagi lé e",
    "ok" : "Ó dáa",
    "contact_name" : "Orúkọ olùbásọ̀rọ̀",
    "reset" : "Tún ṣe",
    "save" : "Pamọ́",
    "address_remove_contact" : "Yọ olùbásọ̀rọ̀ kúrò",
    "address_remove_content" : "Ṣó dá ẹ lójú pé ẹ fẹ́ yọ olùbásọ̀rọ̀ yíyàn kúrò?",


    "authenticated" : "A ti jẹ́rìísí yín",
    "authentication" : "Ìfẹ̀rílàdí",
    "failed_authentication" : "Ìfẹ̀rílàdí pipòfo. ${state_error}",


    "wallet_menu" : "Mẹ́nù",
    "Blocks_remaining" : "Àkójọpọ̀ ${status} kikù",
    "please_try_to_connect_to_another_node" : "Ẹ jọ̀wọ́, gbìyànjú dárapọ̀ mọ́ apẹka mìíràn yí wọlé",
    "xmr_hidden" : "Bìbò",
    "xmr_available_balance" : "Owó tó wà ḿbí",
    "xmr_full_balance" : "Ìyókù owó",
    "send" : "Ránṣẹ́",
    "receive" : "Gbà",
    "transactions" : "Àwọn àránṣẹ́",
    "incoming" : "Wọ́n tó ń bọ̀", 
    "outgoing" : "Wọ́n tó ń jáde",
    "transactions_by_date" : "Àwọn àránṣẹ́ t'á ti fi aago ṣa",
    "trades" : "Àwọn pàṣípààrọ̀",
    "filter_by": "Ṣẹ́ láti",
    "today" : "Lénìí",
    "yesterday" : "Lánàá",
    "received" : "Owó t'á ti gbà",
    "sent" : "Owó t'á ti ránṣẹ́",
    "pending" : " pípẹ́",
    "rescan" : "Tún Wá",
    "reconnect" : "Ṣe àtúnse",
    "wallets" : "Àwọn àpamọ́wọ́",
    "show_seed" : "Wo hóró",
    "show_keys" : "Wo hóró / àwọn kọ́kọ́rọ́",
    "address_book_menu" : "Ìwé Àdírẹ́sì",
    "reconnection" : "Àtúnṣe",
    "reconnect_alert_text" : "Ṣó dá ẹ lójú pé ẹ fẹ́ ṣe àtúnse?",


    "exchange" : "Pàṣípààrọ̀",
    "clear" : "Pa gbogbo nǹkan",
    "refund_address" : "Àdírẹ́sì t'ẹ́ gba owó sí",
    "change_exchange_provider" : "Pààrọ̀ Ilé Ìfowóṣòwò",
    "you_will_send" : "Ṣe pàṣípààrọ̀ láti",
    "you_will_get" : "Ṣe pàṣípààrọ̀ sí",
    "amount_is_guaranteed" : "ó di dandan pé owó á wọlé",
    "amount_is_estimate" : "Ìdíyelé ni iye tó ń bọ̀",
    "powered_by" : "Láti ọwọ́ ${title}",
    "error" : "Àṣìṣe",
    "estimated" : "Ó tó a fojú díwọ̀n",
    "min_value" : "kò gbọ́dọ̀ kéré ju ${value} ${currency}",
    "max_value" : "kò gbọ́dọ̀ tóbi ju ${value} ${currency}",
    "change_currency" : "Pààrọ̀ irú owó",
    "overwrite_amount" : "Pààrọ̀ iye owó",
    "qr_payment_amount" : "Iye owó t'á ránṣé wà nínú àmì ìlujá yìí. Ṣé ẹ fẹ́ pààrọ̀ ẹ̀?",

    "copy_id" : "Ṣẹ̀dà àmì ìdánimọ̀",
    "exchange_result_write_down_trade_id" : "Ẹ jọ̀wọ́, kọ àmì ìdánimọ̀ pàṣípààrọ̀ sílẹ̀ kí tẹ̀síwájú.",
    "trade_id" : "Pàṣípààrọ̀ àmì ìdánimọ̀:",
    "copied_to_clipboard" : "Jíjí wò sí àtẹ àkọsílẹ̀",
    "saved_the_trade_id" : "Mo ti pamọ́ àmì ìdánimọ̀ pàṣípààrọ̀",
    "fetching" : "ń wá",
    "id" : "Àmì Ìdánimọ̀: ",
    "amount" : "Iye: ",
    "payment_id" : "Àmì ìdánimọ̀ àránṣẹ́: ",
    "status" : "Tó ń ṣẹlẹ̀: ",
    "offer_expires_in" : "Ìrònúdábàá máa gbẹ́mìí mì ní: ",
    "trade_is_powered_by" : "${provider} ń fikún pàṣípààrọ̀ yìí lágbára",
    "copy_address" : "Ṣẹ̀dà àdírẹ́sì",
    "exchange_result_confirm" : "T'ẹ́ bá tẹ̀ jẹ́rìí, ẹ máa fi ${fetchingLabel} ${from} ránṣẹ́ láti àpamọ́wọ́ yín t'á pe ${walletName} sí àdírẹ́sì t'ó ṣàfihàn òun lísàlẹ̀. Tàbí ẹ lè fi àpamọ́wọ́ mìíràn yín ránṣẹ́ sí àdírẹ́sì / àmì ìlujá lísàlẹ̀.\n\nẸ jọ̀wọ́ tẹ̀ jẹ́rìí́ tẹ̀síwájú tàbí padà sọ́dọ̀ pààrọ̀ iye náà.",
    "exchange_result_description" : "Ẹ gbọ́dọ̀ ránṣẹ́ iye owó tó pọ̀ jù ${fetchingLabel} ${from} sí àdírẹ́sì tó ṣàfihàn òun lójú tó ń bọ̀. T'ẹ́ bá fi iye tí kò pọ̀ jù ${fetchingLabel} ${from}, a kò lè pàṣípààrọ̀ ẹ̀. A sì kò lè dá a padà fún yín.",
    "exchange_result_write_down_ID" : "*Ẹ jọ̀wọ́, ṣẹ̀dà àmì ìdánimọ̀ yín tó ṣàfihàn òun lókè.",
    "confirm" : "Jẹ́rìísí",
    "confirm_sending" : "Jẹ́rìí sí ránṣẹ́",
    "commit_transaction_amount_fee" : "Jẹ́rìí sí àránṣẹ́\nOwó: ${amount}\nIye àfikún: ${fee}",
    "sending" : "Ó ń ránṣẹ́",
    "transaction_sent" : "Ẹ ti ránṣẹ́ ẹ̀!",
    "expired" : "Kíkú",
    "time" : "${minutes}ìṣj ${seconds}ìṣs",
    "send_xmr" : "Fi XMR ránṣẹ́",
    "exchange_new_template" : "Àwòṣe títun",

    "faq" : "Àwọn ìbéèrè l'a máa ń bèèrè",


    "enter_your_pin" : "Tẹ̀ òǹkà ìdánimọ̀ àdáni yín",
    "loading_your_wallet" : "A ń ṣí àpamọ́wọ́ yín",


    "new_wallet" : "Àpamọ́wọ́ títun",
    "wallet_name" : "Orúkọ àpamọ́wọ́",
    "continue_text" : "Tẹ̀síwájú",
    "choose_wallet_currency" : "Ẹ jọ̀wọ́, yàn irú owó ti àpamọ́wọ́ yín:",


    "node_new" : "Apẹka títun",
    "node_address" : "Àdírẹ́sì apẹka",
    "node_port" : "Ojú ìkànpọ̀ apẹka",
    "login" : "Orúkọ",
    "password" : "Ọ̀rọ̀ aṣínà",
    "nodes" : "Àwọn apẹka",
    "node_reset_settings_title" : "Tún àwọn ààtò ṣe",
    "nodes_list_reset_to_default_message" : "Ṣé ó dá yín lójú pé ẹ fẹ́ yí àwọn ààtò padà?",
    "change_current_node" : "Ṣé ó dá yín lójú pé ẹ fẹ́ pààrọ̀ apẹka lọ́wọ́ sí ${node}?",
    "change" : "Pààrọ̀",
    "remove_node" : "Yọ apẹka kúrò",
    "remove_node_message" : "Ṣé ó da yín lójú pé ẹ fẹ́ yọ apẹka lọwọ́ kúrò?",
    "remove" : "Yọ ọ́ kúrò",
    "delete" : "Pa á",
    "add_new_node" : "Fi apẹka kún",
    "change_current_node_title" : "Pààrọ̀ apẹka lọwọ́",
    "node_test" : "Dánwò",
    "node_connection_successful" : "Ìkànpọ̀ ti dára",
    "node_connection_failed" : "Ìkànpọ̀ ti kùnà",
    "new_node_testing" : "A ń dán apẹka títun wò",


    "use" : "Lo",
    "digit_pin" : "-díjíìtì òǹkà ìdánimọ̀ àdáni",


    "share_address" : "Pín àdírẹ́sì",
    "receive_amount" : "Iye",
    "subaddresses" : "Àwọn àdírẹ́sì kékeré",
    "addresses" : "Àwọn àdírẹ́sì",
    "scan_qr_code" : "Ẹ ya àmì ìlujá láti gba àdírẹ́sì",
    "qr_fullscreen" : "Àmì ìlujá túbọ̀ máa tóbi tí o bá tẹ̀",
    "rename" : "Pààrọ̀ orúkọ",
    "choose_account" : "Yan àkáǹtì",
    "create_new_account" : "Dá àkáǹtì títun",
    "accounts_subaddresses" : "Àwọn àkáǹtì àti àwọn àdírẹ́sì kékeré",


    "restore_restore_wallet" : "Mú àpamọ́wọ́ padà",
    "restore_title_from_seed_keys" : "Fi hóró/kọ́kọ́rọ́ mú padà",
    "restore_description_from_seed_keys" : "Mú àpamọ́wọ́ yín padà láti hóró/kọ́kọ́rọ́ t'ẹ́ ti pamọ́ sí ibi láìléwu",
    "restore_next" : "Tẹ̀síwájú",
    "restore_title_from_backup" : "Fi ẹ̀dà nípamọ́ mú padà",
    "restore_description_from_backup" : "Ẹ lè fi ẹ̀dà nípamọ́ yín mú odindi Cake Wallet áàpù padà.",
    "restore_seed_keys_restore" : "Mú hóró/kọ́kọ́rọ́ padà",
    "restore_title_from_seed" : "Fi hóró mú padà",
    "restore_description_from_seed" : "Ẹ mú àpamọ́wọ́ yín padà láti àkànpọ̀ ọlọ́rọ̀ ẹ̀ẹ̀marùndínlọgbọ̀n tàbí ti mẹ́talá.",
    "restore_title_from_keys" : "Fi kọ́kọ́rọ́ ṣẹ̀dá",
    "restore_description_from_keys" : "Mú àpamọ́wọ́ yín padà láti àwọn àtẹ̀ nípamọ́ láti àwọn kọ́kọ́rọ́ àdáni yín",
    "restore_wallet_name" : "Orúkọ àpamọ́wọ́",
    "restore_address" : "Àdírẹ́sì",
    "restore_view_key_private" : "kọ́kọ́rọ́ ìrán àdáni",
    "restore_spend_key_private" : "kọ́kọ́rọ́ àdáni fún níná",
    "restore_recover" : "Mú padà",
    "restore_wallet_restore_description" : "Ìṣapẹrẹ mú àpamọ́wọ́ padà",
    "restore_new_seed" : "Hóró títun",
    "restore_active_seed" : "Hóró lọ́wọ́",
    "restore_bitcoin_description_from_seed" : "Mú àpamọ́wọ́ yín padà láti àkànpọ̀ ọlọ́rọ̀ ẹ̀ẹ̀mẹrinlélógun",
    "restore_bitcoin_description_from_keys" : "Mú àpamọ́wọ́ yín padà láti ọ̀rọ̀ WIF t'á ti dá láti kọ́kọ́rọ́ àdáni yín",
    "restore_bitcoin_title_from_keys" : "Mú padà láti WIF",
    "restore_from_date_or_blockheight" : "Ẹ jọ̀wọ́, tẹ̀ ìgbà ọjọ́ díẹ̀ k'ẹ́ tó ti dá àpamọ́wọ́ yìí. Tàbí ẹ lè tẹ̀ ẹ́ t'ẹ́ bá mọ gíga àkójọpọ̀.",


    "seed_reminder" : "Ẹ jọ̀wọ́, kọ wọnyí sílẹ̀ k'ẹ́ tó pàdánù ẹ̀rọ ìbánisọ̀rọ̀ yín",
    "seed_title" : "Hóró",
    "seed_share" : "Pín hóró",
    "copy" : "Ṣẹ̀dà",


    "seed_language_choose" : "Ẹ jọ̀wọ́ yan èdè hóró:",
    "seed_choose" : "Yan èdè hóró",
    "seed_language_next" : "Tẹ̀síwájú",
    "seed_language_english" : "Èdè Gẹ̀ẹ́sì",
    "seed_language_chinese" : "Èdè Ṣáínà",
    "seed_language_dutch" : "Èdè Nẹ́dálaǹdì",
    "seed_language_german" : "Èdè Jámánì",
    "seed_language_japanese" : "Èdè Jẹ́páànì",
    "seed_language_portuguese" : "Èdè Potogí",
    "seed_language_russian" : "Èdè Rọ́síà",
    "seed_language_spanish" : "Èdè Sípéènì",
    "seed_language_french": "Èdè Fránsì",
    "seed_language_italian": "Èdè Itálíà",


    "send_title" : "Ránṣẹ́",
    "send_your_wallet" : "Àpamọ́wọ́ yín",
    "send_address" : "${cryptoCurrency} àdírẹ́sì",
    "send_payment_id" : "Àmì ìdánimọ̀ àránṣẹ́ (ìyàn nìyí)",
    "all" : "Gbogbo",
    "send_error_minimum_value" : "Ránṣẹ́ owó kò kéré dé 0.01",
    "send_error_currency" : "Ó yẹ kí òǹkà dá wà nínu iye",
    "send_estimated_fee" : "Iye àfikún l'a fojú díwọ̀n:",
    "send_priority" : "${transactionPriority} agbára ni owó àfikún lọ́wọ́lọ́wọ́.\nẸ lè pààrọ̀ iye agbára t'ẹ fikún àránṣẹ́ lórí àwọn ààtò",
    "send_creating_transaction" : "Ńṣe àránṣẹ́",
    "send_templates" : "Àwọn àwòṣe",
    "send_new" : "Títun",
    "send_amount" : "Iye:",
    "send_fee" : "Owó àfikún:",
    "send_name" : "Orúkọ",
    "send_got_it" : "Ó dáa",
    "send_sending" : "Ń Ránṣẹ́...",
    "send_success" : "A ti ránṣẹ́ ${crypto} yín dáadáa",


    "settings_title" : "Àwọn ààtò",
    "settings_nodes" : "Àwọn apẹka",
    "settings_current_node" : "Apẹka lọ́wọ́lọ́wó",
    "settings_wallets" : "Àwọn àpamọ́wọ́",
    "settings_display_balance" : "Ṣàfihàn ìyókù owó",
    "settings_currency" : "Iye owó",
    "settings_fee_priority" : "Bí iye àfikún ṣe ṣe pàtàkì",
    "settings_save_recipient_address" : "Pamọ́ àdírẹ́sì olùgbà",
    "settings_personal" : "Àdáni",
    "settings_change_pin" : "Pààrọ̀ òǹkà ìdánimọ̀ àdáni",
    "settings_change_language" : "Pààrọ̀ èdè",
    "settings_allow_biometrical_authentication" : "Fi àyè gba ìfẹ̀rílàdí biometrical",
    "settings_dark_mode" : "Ṣókùnkùn Áápù",
    "settings_transactions" : "Àwọn àránṣẹ́",
    "settings_trades" : "Àwọn pàṣípààrọ̀",
    "settings_display_on_dashboard_list" : "Ṣàfihàn lórí àkọsílẹ̀ tá fihàn",
    "settings_all" : "Gbogbo",
    "settings_only_trades" : "Àwọn pàṣípààrọ̀ nìkan",
    "settings_only_transactions" : "Àwọn àránṣẹ́ nìkan",
    "settings_none" : "Kòsóhun",
    "settings_support" : "Ìranlọ́wọ́",
    "settings_terms_and_conditions" : "Àwọn Òfin àti àwọn Àjọrò",
    "pin_is_incorrect" : "òǹkà ìdánimọ̀ àdáni kò yẹ́",


    "setup_pin" : "Setup òǹkà ìdánimọ̀ àdáni",
    "enter_your_pin_again" : "Tún òǹkà ìdánimọ̀ àdáni yín tẹ̀",
    "setup_successful" : "Òǹkà ìdánimọ̀ àdáni yín ti ṣe!",


    "wallet_keys" : "Hóró/kọ́kọ́rọ́ àpamọ́wọ́",
    "wallet_seed" : "Hóró àpamọ́wọ́",
    "private_key" : "Kọ́kọ́rọ́ àdáni",
    "public_key" : "Kọ́kọ́rọ́ tó kò àdáni",
    "view_key_private" : "Kọ́kọ́rọ́ ìwò (àdáni)",
    "view_key_public" : "Kọ́kọ́rọ́ ìwò (kò àdáni)",
    "spend_key_private" : "Kọ́kọ́rọ́ sísan (àdáni)",
    "spend_key_public" : "Kọ́kọ́rọ́ sísan (kò àdáni)",
    "copied_key_to_clipboard" : "Ti ṣeda ${key} sí àtẹ àkọsílẹ̀",


    "new_subaddress_title" : "Àdírẹ́sì títun",
    "new_subaddress_label_name" : "Orúkọ",
    "new_subaddress_create" : "Ṣe é",

    "address_label" : "Orúkọ àdírẹ́sì",

    "subaddress_title" : "Àkọsílẹ̀ ni nínú àwọn àdírẹ́sì tíwọn rẹ̀lẹ̀",


    "trade_details_title" : "Ìsọfúnni pàṣípààrọ̀",
    "trade_details_id" : "Àmì ìdánimọ̀:",
    "trade_details_state" : "Tó ń ṣẹlẹ̀",
    "trade_details_fetching" : "Ń mú wá",
    "trade_details_provider" : "Ilé pàṣípààrọ̀",
    "trade_details_created_at" : "Ṣíṣe ní",
    "trade_details_pair" : "Àwọn irú owó t'á pàṣípààrọ̀ jọ",
    "trade_details_copied" : "Ti ṣeda ${title} sí àtẹ àkọsílẹ̀",


    "trade_history_title" : "Ìtan pàṣípààrọ̀",


    "transaction_details_title" : "Àránṣẹ́ ìsọfúnni",
    "transaction_details_transaction_id" : "Àmì ìdánimọ̀ àránṣẹ́",
    "transaction_details_date" : "Ìgbà",
    "transaction_details_height" : "Gíga",
    "transaction_details_amount" : "Iye owó",
    "transaction_details_fee" : "Iye àfikún",
    "transaction_details_copied" : "A ṣeda ${title} sí àkọsílẹ̀",
    "transaction_details_recipient_address" : "Àwọn àdírẹ́sì olùgbà",


    "wallet_list_title" : "Àpamọ́wọ́ Monero",
    "wallet_list_create_new_wallet" : "Ṣe àpamọ́wọ́ títun",
    "wallet_list_restore_wallet" : "Restore àpamọ́wọ́",
    "wallet_list_load_wallet" : "Load àpamọ́wọ́",
    "wallet_list_loading_wallet" : "Ń ṣí àpamọ́wọ́ ${wallet_name}",
    "wallet_list_failed_to_load" : "Ti kùnà ṣí́ àpamọ́wọ́ ${wallet_name}. ${error}",
    "wallet_list_removing_wallet" : "Ń yọ àpamọ́wọ́ ${wallet_name} kúrò",
    "wallet_list_failed_to_remove" : "Ti kùnà yọ ${wallet_name} àpamọ́wọ́ kúrò. ${error}",


    "widgets_address" : "Àdírẹ́sì",
    "widgets_restore_from_blockheight" : "Dá padà sípò láti gíga àkójọpọ̀",
    "widgets_restore_from_date" : "Dá padà sípò láti ìgbà",
    "widgets_or" : "tàbí",
    "widgets_seed" : "Hóró",


    "router_no_route" : "Ọ̀nà kò sí fún ${name}",


    "error_text_account_name" : "Orúkọ àkáǹtì lè ni nìkan nínú ẹyọ ọ̀rọ̀ àti òǹkà\nGígun rẹ̀ kò gbọ́dọ̀ kéré ju oókan. Gígun rẹ̀ sì kò gbọ́dọ̀  tóbi ju márùndínlógún.",
    "error_text_contact_name" : "Orúkọ olùbásọ̀rọ̀ kò lè ni nínú ` , ' \" ẹyọ ọ̀rọ̀.\nIye ẹyọ ọ̀rọ̀ kò gbọ́dọ̀ kéré ju oókan. Ó sì kò gbọ́dọ̀ tóbi ju méjìlélọ́gbọ̀n.",
    "error_text_address" : "Àdírẹ́sì àpamọ́wọ́ gbọ́dọ̀ báramu irú owó",
    "error_text_node_address" : "Ẹ jọ̀wọ́ tẹ̀ àdírẹ́sì iPv4",
    "error_text_node_port" : "Ojú ìkànpọ̀ apẹka lè ni nìkan nínú òǹkà l'áàárín òdo àti márùn-úndínlógojí lé ní ẹ̀ẹ́dẹgbẹ̀ta lé ní ọ̀kẹ́ mẹ́ta lé ní ẹ̀ẹ́dẹ́gbàta",
    "error_text_payment_id" : "Iye ẹyọ ọ̀rọ̀ nínú àmì ìdánimọ̀ àránṣẹ́ gbọ́dọ̀ wà l'áàárín aárùndínlógún dé ẹẹ́rinlélọ́gọ́ta.",
    "error_text_xmr" : "Iye XMR kò lè tóbi ju ìyókù.\nIye díjíìtì léyìn ẹsẹ kò gbọ́dọ̀ tóbi ju eéjìlá.",
    "error_text_fiat" : "Iye àránṣẹ́ kò tóbi ju ìyókù owó.\nIye díjíìtì léyìn ẹsẹ kò gbọ́dọ̀ tóbi ju eéjì.",
    "error_text_subaddress_name" : "Orúkọ àdírẹ́sì tó rẹ̀lẹ̀ kò ni nínú àmì ` , ' \"\nIye ẹyọ ọ̀rọ̀ gbọ́dọ̀ wà láàárín oókan àti ogún",
    "error_text_amount" : "Iye lè ni nìkan nínú àwọn òǹkà",
    "error_text_wallet_name" : "Orúkọ àpamọ́wọ́ lè ni nìkan nínú àwọn òǹkà àti ẹyọ ọ̀rọ̀ àti àmì _ -\nIye ẹyọ ọ̀rọ̀ gbọ́dọ̀ wà láàárín 1 àti 33",
    "error_text_keys" : "Àwọn kọ́kọ́rọ́ àpamọ́wọ́ gbọ́dọ̀ ní ẹyọ ọ̀rọ̀ mẹ́rinlélọ́gọ́ta lílà mẹ́rìndínlógún",
    "error_text_crypto_currency" : "Iye díjíìtì léyìn ẹsẹ kò gbọ́dọ̀ tóbi ju eéjìlá.",
    "error_text_minimal_limit" : "A kò tí ì ṣe pàṣípààrọ̀ tí ${provider} nítorí iye kéré ju ${min} ${currency}",
    "error_text_maximum_limit" : "A kò tí ì ṣe pàṣípààrọ̀ tí ${provider} nítorí iye tóbi ju ${min} ${currency}",
    "error_text_limits_loading_failed" : "A kò tí ì ṣe pàṣípààrọ̀ tí ${provider} nítorí a ti kùnà mú àwọn ààlà wá",
    "error_text_template" : "Orúkọ àwòṣe àti àdírẹ́sì kò lè ni nínú àwọn àmì ` , ' \"\nIye ẹyọ ọ̀rọ̀ náà gbọ́dọ̀ jẹ́ láàárín 1 àti 106",


    "auth_store_ban_timeout" : "ìfòfindè ti gbẹ́mìí mì",
    "auth_store_banned_for" : "A ti fòfin de ẹ̀ nítorí ",
    "auth_store_banned_minutes" : " ìṣéjú",
    "auth_store_incorrect_password" : "Òǹkà ìdánimọ̀ àdáni kọ́ ni èyí",
    "wallet_store_monero_wallet" : "Àpamọ́wọ́ Monero",
    "wallet_restoration_store_incorrect_seed_length" : "Gígùn hóró tí a máa ń lò kọ́ ni èyí",


    "full_balance" : "Ìyókù owó kíkún",
    "available_balance" : "Ìyókù owó tó wà níbẹ̀",
    "hidden_balance" : "Ìyókù owó dídé",


    "sync_status_syncronizing" : "Ń MÚDỌ́GBA",
    "sync_status_syncronized" : "TI MÚDỌ́GBA",
    "sync_status_not_connected" : "KÒ TI DÁRAPỌ̀ MỌ́ Ọ",
    "sync_status_starting_sync" : "Ń BẸ̀RẸ̀ RẸ́",
    "sync_status_failed_connect" : "ÌKÀNPỌ̀ TI KÚ",
    "sync_status_connecting" : "Ń DÁRAPỌ̀ MỌ́",
    "sync_status_connected" : "TI DÁRAPỌ̀ MỌ́",
    "sync_status_attempting_sync" : "Ń GBÌYÀNJÚ MÚDỌ́GBA",


    "transaction_priority_slow" : "Díẹ̀",
    "transaction_priority_regular" : "Àjùmọ̀lò",
    "transaction_priority_medium" : "L’áàárín",
    "transaction_priority_fast" : "Yára",
    "transaction_priority_fastest" : "Yá jù lọ",


    "trade_for_not_created" : "A kò tí ì ṣe pàṣípààrọ̀ ${title}",
    "trade_not_created" : "A kò tí ì ṣe pàṣípààrọ̀ náà",
    "trade_id_not_found" : "Trade ${tradeId} ti a ko ba ri ninu ${title}.",
    "trade_not_found" : "A kò tí ì wá pàṣípààrọ̀.",


    "trade_state_pending" : "Pípẹ́",
    "trade_state_confirming" : "Ń jẹ́rìí",
    "trade_state_trading" : "Ń ṣe pàṣípààrọ̀",
    "trade_state_traded" : "Ti ṣe pàṣípààrọ̀",
    "trade_state_complete" : "Ti ṣetán",
    "trade_state_to_be_created" : "Máa ṣe",
    "trade_state_unpaid" : "Kò tíì san",
    "trade_state_underpaid" : "Ti san iye tó kéré jù",
    "trade_state_paid_unconfirmed" : "Ti san. A kò tíì jẹ́rìí ẹ̀",
    "trade_state_paid" : "Ti san",
    "trade_state_btc_sent" : "Ti san BTC",
    "trade_state_timeout" : "Ti gbẹ́mìí mì",
    "trade_state_created" : "Ti ṣe",
    "trade_state_finished" : "Ti ṣetán",

    "change_language" : "Pààrọ̀ èdè",
    "change_language_to" : "Pààrọ̀ èdè sí ${language}?",

    "paste" : "Fikún ẹ̀dà yín",
    "restore_from_seed_placeholder" : "Ẹ jọ̀wọ́ tẹ̀ hóró yín tàbí fikún ẹ̀dà hóró ḿbí.",
    "add_new_word" : "Fikún ọ̀rọ̀ títun",
    "incorrect_seed" : "Ọ̀rọ̀ tí a tẹ̀ kì í ṣe èyí.",

    "biometric_auth_reason" : "Ya ìka ọwọ́ yín láti ṣe ìfẹ̀rílàdí",
    "version" : "Àtúnse ${currentVersion}",

    "extracted_address_content" : "Ẹ máa máa fi owó ránṣẹ́ sí\n${recipient_name}",

    "card_address" : "Àdírẹ́sì:",
    "buy" : "Rà",
    "sell": "Tà",

    "placeholder_transactions" : "A máa fihàn àwọn àránṣẹ́ yín ḿbí",
    "placeholder_contacts" : "A máa fihàn àwọn olùbásọ̀rọ̀ yín ḿbí",

    "template" : "Àwòṣe",
    "confirm_delete_template" : "Ìṣe yìí máa yọ àwòṣe yìí kúrò. Ṣé ẹ fẹ́ tẹ̀síwájú?",
    "confirm_delete_wallet" : "Ìṣe yìí máa yọ àpamọ́wọ́ yìí kúrò. Ṣé ẹ fẹ́ tẹ̀síwájú?",

    "picker_description" : "Ẹ jọ̀wọ́ pààrọ̀ owó tí ẹ pàṣípààrọ̀ jọ yín lákọ̀ọ́kọ́ kí ẹ yán ChangeNOW tàbí MorphToken",

    "change_wallet_alert_title" : "Ẹ pààrọ̀ àpamọ́wọ́ yìí",
    "change_wallet_alert_content" : "Ṣe ẹ fẹ́ pààrọ̀ àpamọ́wọ́ yìí sí ${wallet_name}?",

    "creating_new_wallet" : "Ń dá àpamọ́wọ́ títun",
    "creating_new_wallet_error" : "Àṣìṣe: ${description}",

    "seed_alert_title" : "Ẹ wo",
    "seed_alert_content" : "Hóró ni ọ̀nà nìkan kí ṣẹ̀dà àpamọ́wọ́ yín. Ṣé ẹ ti kọ ọ́ sílẹ̀?",
    "seed_alert_back" : "Padà sọ́dọ̀",
    "seed_alert_yes" : "Mo ti kọ ọ́",

    "exchange_sync_alert_content" : "Ẹ jọ̀wọ́ dúró kí a ti múdọ́gba àpamọ́wọ́ yín",

    "pre_seed_title" : "Ó TI ṢE PÀTÀKÌ",
    "pre_seed_description" : "Ẹ máa wo àwọn ọ̀rọ̀ ${words} lórí ojú tó ń bọ̀. Èyí ni hóró aládàáni yín tó kì í jọra. Ẹ lè fi í nìkan dá àpamọ́wọ́ yín padà sípò tí àṣìṣe tàbí ìbàjẹ́ bá ṣẹlẹ̀. Hóró yín ni ẹ gbọ́dọ̀ kọ sílẹ̀ àti pamọ́ síbí tó kò léwu níta Cake Wallet.",
    "pre_seed_button_text" : "Mo ti gbọ́. O fi hóró mi hàn mi",

    "provider_error" : "Àṣìṣe ${provider}",

    "use_ssl" : "Lo SSL",
    "trusted" : "A ti fọkàn ẹ̀ tán",

    "color_theme" : "Àwọn ààtò àwọ̀",
    "light_theme" : "Funfun bí eérú",
    "bright_theme" : "Funfun",
    "dark_theme" : "Dúdú",
    "enter_your_note" : "Tẹ̀ àkọsílẹ̀ yín",
    "note_optional" : "Àkọsílẹ̀ (ìyàn nìyí)",
    "note_tap_to_change" : "Àkọsílẹ̀  (ẹ tẹ̀ láti pààrọ̀)",
    "view_in_block_explorer" : "Wo lórí olùṣèwádìí àkójọpọ̀",
    "view_transaction_on" : "Wo pàṣípààrọ̀ lórí ",
    "transaction_key" : "Kọ́kọ́rọ́ pàṣípààrọ̀",
    "confirmations" : "Àwọn ẹ̀rí",
    "recipient_address" : "Àdírẹ́sì olùgbà",

    "extra_id" : "Àmì ìdánimọ̀ tó fikún:",
    "destination_tag" : "Orúkọ tí ìbí tó a ránṣẹ́ sí:",
    "memo" : "Àkọsílẹ̀:",

    "backup" : "Ṣẹ̀dà",
    "change_password" : "Pààrọ̀ ọ̀rọ̀ aṣínà",
    "backup_password" : "Ṣẹ̀dà ọ̀rọ̀ aṣínà",
    "write_down_backup_password" : "Ẹ jọ̀wọ́ ẹ̀dà ọ̀rọ̀ aṣínà ti ẹ̀dà nípamọ́ yín tó máa ń bá yín ṣí àkọsílẹ̀ yín l'ẹ kọ sílẹ̀.",
    "export_backup" : "Sún ẹ̀dà nípamọ́ síta",
    "save_backup_password" : "Ẹ jọ̀wọ́ dájú pé ẹ ti pamọ́ ọ̀rọ̀ aṣínà ti ẹ̀dà nípamọ́ yín. Ti ẹ kò bá ni í, ẹ kò lè ṣí àwọn àkọsílẹ̀ nípamọ́ yín.",
    "backup_file" : "Ṣẹ̀dà akọsílẹ̀",

    "edit_backup_password" : "Pààrọ̀ ọ̀rọ̀ aṣínà",
    "save_backup_password_alert" : "Pamọ́ ọ̀rọ̀ aṣínà ti ẹ̀dà",
    "change_backup_password_alert" : "Ẹ kò lè fi ọ̀rọ̀ aṣínà títun ti ẹ̀dà nípamọ́ ṣí àwọn àkọsílẹ̀ nípamọ́ tẹ́lẹ̀tẹ́lẹ̀ yín. Ẹ máa fi ọ̀rọ̀ aṣínà ti ẹ̀dà nípamọ́ títun ṣí àwọn àkọsílẹ̀ nípamọ́ títun nìkan. Ṣé ó dá ẹ lójú pé ẹ fẹ́ pààrọ̀  aṣínà ti ẹ̀dà nípamọ́?",

    "enter_backup_password" : "Tẹ̀ ọ̀rọ̀ aṣínà ti ẹ̀dà ḿbí",
    "select_backup_file" : "Select backup file",
    "import" : "Gba wọlé",
    "please_select_backup_file" : "Ẹ jọ̀wọ́ yan àkọsílẹ̀ nípamọ́ àti tẹ̀ ọ̀rọ̀ aṣínà ti ẹ̀dà.",

    "fixed_rate" : "Iye t'á ṣẹ́ owó sí ò ní pààrọ̀",
    "fixed_rate_alert" : "Ẹ lè tẹ̀ iye owó tó ń bọ̀ tí iye t'a ṣẹ́ owó sí bá is checked. Ṣé ẹ fẹ́ sún ipò ti iye t'á ṣẹ́ owó sí ò ní pààrọ̀ mọ́?",

    "xlm_extra_info" : "Ẹ jọ̀wọ́ ẹ kò gbàgbé pèsè àmì ìdánimọ̀ àkọsílẹ̀ t'ẹ́ ń bá ránṣẹ́ pàṣípààrọ̀ ti XLM yín sí ilé ìfowóṣòwò",
    "xrp_extra_info" : "Ẹ jọ̀wọ́ ẹ kò gbàgbé pèsè orúkọ̀ àdírẹ́sì ti a ránṣẹ́ sí t'ẹ́ bá ránṣẹ pàṣípààrọ̀ ti XRP yín sílé ìfowóṣòwò",

    "exchange_incorrect_current_wallet_for_xmr" : "T'ẹ́ bá fẹ́ pàṣípààrọ̀ XMR láti ìyókù owó Cake Wallet yín, ẹ jọ̀wọ́ kọ́kọ́ sún àpamọ́wọ́ Monero mọ́.",
    "confirmed" : "A ti jẹ́rìí ẹ̀",
    "unconfirmed" : "A kò tí ì jẹ́rìí ẹ̀",
    "displayable" : "A lè ṣàfihàn ẹ̀",

    "submit_request" : "Ṣé ìbéèrè",

    "buy_alert_content" : "A jẹ́ kí ríra Bitcoin àti Litecoin nìkan. Ẹ jọ̀wọ́ dá tàbí sún àpamọ́wọ́ ti Bitcoin yín tàbí àpamọ́wọ́ ti Litecoin yín mọ́, t'ẹ́ bá fẹ́ ra Bitcoin tàbí Litecoin.",
    "sell_alert_content": "A jẹ́ kí títa Bitcoin nìkan. Ẹ jọ̀wọ́ dá tàbí sún àpamọ́wọ́ ti Bitcoin yín mọ́, t'ẹ́ bá fẹ́ ta Bitcoin.",

    "outdated_electrum_wallet_description" : "Àwọn àpamọ́wọ́ títun Bitcoin ti a ti dá nínú Cake Wallet lọ́wọ́lọ́wọ́. Àwọn àpamọ́wọ́ títun t'á dá nínú Cake Wallet ni hóró tó ní ọ̀rọ̀ mẹ́rinlélógún. Ẹ gbọ́dọ̀ dá àpamọ́wọ́. Ẹ sì sún gbogbo owó yín sí àpamọ́wọ́ títun náà tó dá lórí ọ̀rọ̀ mẹ́rinlélógún. Ẹ sì gbọ́dọ̀ yé lo àwọn àpamọ́wọ́ tó dá lórí hóró tó ní ọ̀rọ̀ méjìlá. Ẹ jọ̀wọ́ ṣe èyí láìpẹ́ kí ẹ ba owó yín.",
    "understand" : "Ó ye mi",

    "apk_update" : "Àtúnse áàpù títun wà",

    "buy_bitcoin" : "Ra Bitcoin",
    "buy_with" : "Rà pẹ̀lú",
    "moonpay_alert_text" : "Iye owó kò gbọ́dọ̀ kéré ju ${minAmount} ${fiatCurrency}",

    "outdated_electrum_wallet_receive_warning": "Ẹ KÒ FI BITCOIN SÍ ÀPAMỌ́WỌ́ YÌÍ t'á ti dá a nínú Cake Wallet àti àpamọ́wọ́ yìí ni hóró ti ọ̀rọ̀ méjìlá. A lè pàdánù BTC t'á ránṣẹ́ sí àpamọ́wọ́ yìí. Ẹ dá àpamọ́wọ́ títun tó ni hóró tó ni ọ̀rọ̀ mẹ́rinlélógún (Ẹ tẹ àkọsílẹ̀ tó wa l’ókè l'ọ́tún nígbàna, ẹ sì yan àwọn àpamọ́wọ́ nígbàna, ẹ sì yan Dá Àpamọ́wọ́ Títun nígbàna, ẹ sì yan Bitcoin) àti sún Bitcoin yín síbẹ̀ ní sinsìn yẹn. Àwọn àpamọ́wọ́ títun (hóró ni ọ̀rọ̀ mẹ́rinlélógún) láti Cake Wallet wa láìléwu.",
    "do_not_show_me": "Kò fi eléyìí hàn mi mọ́",

    "unspent_coins_title" : "Àwọn owó ẹyọ t'á kò tí ì san",
    "unspent_coins_details_title" : "Àwọn owó ẹyọ t'á kò tí ì san",
    "freeze" : "Tì pa",
    "frozen" : "Ó l'a tì pa",
    "coin_control" : "Ìdarí owó ẹyọ (ìyàn nìyí)",

    "address_detected" : "A ti gbọ́ àdírẹ́sì",
    "address_from_domain" : "Àdírẹ́sì yìí wá láti ${domain} lórí Unstoppable Domains",

    "add_receiver" : "Fikún àdírẹ́sì mìíràn (ìyàn nìyí)",

    "manage_yats" : "Bójú Yats",
    "yat_alert_title" : "Lílò Yat láti ránṣẹ́ àti gba owó dùn ṣe pọ̀ ju lọ",
    "yat_alert_content" : "Àwọn olùṣàmúlò ti Cake Wallet lè fi orúkọ olùṣàmúlò t'á dá lórí emójì tó kì í jọra ránṣẹ́ àti gba gbogbo àwọn irú owó tíwọn yàn láàyò lọ́wọ́lọ́wọ́.",
    "get_your_yat" : "Gba Yat yín",
    "connect_an_existing_yat" : "So Yat wíwà",
    "connect_yats": "So àwọn Yat",
    "yat_address" : "Àdírẹ́sì Yat",
    "yat" : "Yat",
    "address_from_yat" : "Àdírẹ́sì yìí wá láti ${emoji} lórí Yat",
    "yat_error" : "Àṣìṣe Yat",
    "yat_error_content" : "Kò sí àdírẹ́sìkádírẹ́sì tó so Yat yìí. Ẹ gbìyànjú Yat mìíràn",
    "choose_address" : "\n\nẸ jọ̀wọ́ yan àdírẹ́sì:",
    "yat_popup_title" : "Ẹ lè dá àpamọ́wọ́ yín láti emójì.",
    "yat_popup_content" : "Ẹ lè fi Yat yín (orúkọ olùṣàmúlò kúkurú t'á dá lórí emójì) ránṣẹ́ àti gba owó nínú Cake Wallet lọ́wọ́lọ́wọ́. Bójú Yats lórí ojú ààtò lígbàkúgbà.",
    "second_intro_title" : "Àdírẹ́sì kan t'á dá láti emójì tó pàṣẹ gbogbo ohun wà",
    "second_intro_content" : "Àdírẹ́sì kan tó dá lórí emójì tó kì í jọra ni Yat yín. Ó rọ́pò gbogbo àwọn àdírẹ́sì gígùn yín tó dá lórí ìlà mẹ́rìndínlógún ti gbogbo àwọn iye owó yín.",
    "third_intro_title" : "Àlàáfíà ni Yat àti àwọn ìmíìn jọ wà",
    "third_intro_content" : "A sì lè lo Yats níta Cake Wallet. A lè rọ́pò Àdírẹ́sì kankan àpamọ́wọ́ fún Yat!",
    "learn_more" : "Túbọ̀ kọ́",
    "search": "Wá",
    "search_language": "Wá èdè",
    "search_currency": "Wá irú owó",
    "new_template" : "Àwòṣe títun",
    "electrum_address_disclaimer": "A dá àwọn àdírẹ́sì títun ní gbogbo àwọn ìgbà t'ẹ́ lo ó kan ṣùgbọ́n ẹ lè tẹ̀síwájú lo àwọn àdírẹ́sì tẹ́lẹ̀tẹ́lẹ̀.",
    "wallet_name_exists": "Ẹ ti ní àpamọ́wọ́ pẹ̀lú orúkọ̀ yẹn. Ẹ jọ̀wọ́ yàn orúkọ̀ tó yàtọ̀ tàbí pààrọ̀ orúkọ ti àpamọ́wọ́ tẹ́lẹ̀.",
    "market_place": "Ọjà",
    "cake_pay_title": "Àwọn káàdì ìrajà t'á lò nínú ìtajà kan ti Cake Pay",
    "cake_pay_subtitle": "Ra àwọn káàdì ìrajà t'á lò nínú ìtajà kan fún owó tí kò pọ̀ (USA nìkan)",
    "cake_pay_web_cards_title": "Àwọn káàdì wẹ́ẹ̀bù ti Cake Pay",
    "cake_pay_web_cards_subtitle": "Ra àwọn káàdì ìrajà t'á lò nínú ìtajà kan àti àwọn káàdì náà t'á lè lò níbikíbi",
    "about_cake_pay": "Cake Pay jẹ́ kí ẹ lè fi owó wẹ́ẹ̀bù ra àwọn káàdì ìrajà t'á lò nínú iye ìtajà kan. Ẹ lè san wọn láìpẹ́ nítajà 150,000 nínú Amẹ́ríkà.",
    "cake_pay_account_note": "Ẹ fi àdírẹ́sì ímeèlì nìkan forúkọ sílẹ̀ k'ẹ́ rí àti ra àwọn káàdì. Ẹ lè fi owó tó kéré jù ra àwọn káàdì kan!",
    "already_have_account": "Ṣé ẹ ti ní àkáǹtì?",
    "create_account": "Dá àkáǹtì",
    "privacy_policy": "Òfin Aládàáni",
    "welcome_to_cakepay": "Ẹ káàbọ̀ sí Cake Pay!",
    "sign_up": "Forúkọ sílẹ̀",
    "forgot_password": "Ẹ ti gbàgbé ọ̀rọ̀ aṣínà",
    "reset_password": "Tún ọ̀rọ̀ aṣínà ṣe",
    "gift_cards": "Àwọn káàdì ìrajà t'á lò nínú iye kan ìtajà",
    "setup_your_debit_card": "Dá àwọn káàdì ìrajà yín",
    "no_id_required": "Ẹ kò nílò àmì ìdánimọ̀. Ẹ lè fikún owó àti san níbikíbi",
    "how_to_use_card": "Báyìí ni wọ́n ṣe ń lo káàdì yìí.",
    "purchase_gift_card": "Ra káàdì ìrajà t'á lò nínú irú kan ìtajà",
    "verification": "Ìjẹ́rìísí",
    "fill_code": "Ẹ jọ̀wọ́ tẹ̀ ọ̀rọ̀ ìjẹ́rìísí t'á ti ránṣẹ́ sí ímeèlì yín.",
    "dont_get_code": "Ṣé ẹ ti gba ọ̀rọ̀ ìdánimọ̀?",
    "resend_code": "Ẹ jọ̀wọ́ tún un ránṣé",
    "debit_card": "Káàdì ìrajà",
    "cakepay_prepaid_card": "Káàdì ìrajà ti CakePay",
    "no_id_needed": "Ẹ kò nílò àmì ìdánimọ̀!",
    "frequently_asked_questions": "Àwọn ìbéèrè la máa ń béèrè",
    "debit_card_terms": "Òfin ti olùṣe àjọrò káàdì ìrajà bójú irú ọ̀nà t'á pamọ́ àti a lo òǹkà ti káàdì ìrajà yín (àti ọ̀rọ̀ ìdánimọ̀ tí káàdì náà) nínú àpamọ́wọ́ yìí.",
    "please_reference_document": "Ẹ jọ̀wọ́ fi àwọn àkọsílẹ̀ l’ábẹ́ túbọ̀ mọ ìsọfúnni.",
    "cardholder_agreement": "Àjọrò olùṣe káàdì ìrajà",
    "e_sign_consent": "Jẹ́rìí sí lórí ayélujára",
    "agree_and_continue": "Jọ Rò àti Tẹ̀síwájú",
    "email_address": "Àdírẹ́sì ímeèlì",
    "agree_to": "Tẹ́ ẹ bá dá àkáǹtì ẹ jọ rò ",
    "and": "àti",
    "enter_code": "Tẹ̀ ọ̀rọ̀",
    "congratulations": "Ẹ kúuṣẹ́ ooo!",
    "you_now_have_debit_card": "Ẹ ni káàdì ìrajà lọ́wọ́lọ́wọ́",
    "min_amount" : "kò kéré ju: ${value}",
    "max_amount" : "kò tóbi ju: ${value}",
    "enter_amount": "Tẹ̀ iye",
    "billing_address_info": "Tí ọlọ́jà bá bèèrè àdírẹ́sì sísan yín, fún òun ni àdírẹ́sì t'á ránṣẹ́ káàdì yìí sí",
    "order_physical_card": "Bèèrè káàdì t'ara",
    "add_value": "Fikún owó",
    "activate": "Fi àyè gba",
    "get_a": "Gba ",
    "digital_and_physical_card": " káàdì ìrajà t'ara àti ti ayélujára",
    "get_card_note": " t'ẹ lè fikún owó ayélujára. Ẹ kò nílò ìṣofúnni àfikún!",
    "signup_for_card_accept_terms": "Ẹ f'orúkọ sílẹ̀ láti gba káàdì àti àjọrò.",
    "add_fund_to_card": "Ẹ fikún owó sí àwọn káàdì (kò tóbi ju ${value})",
    "use_card_info_two": "A pààrọ̀ owó sí owó Amẹ́ríkà tó bá wà nínú àkanti t'á ti fikún tẹ́lẹ̀tẹ́lẹ̀. A kò kó owó náà nínú owó ayélujára.",
    "use_card_info_three": "Ẹ lo káàdí ayélujára lórí wẹ́ẹ̀bù tàbí ẹ lò ó lórí àwọn ẹ̀rọ̀ ìrajà tíwọn kò kò.",
    "optionally_order_card": "Ẹ lè fi ìyàn bèèrè káàdì t'ara.",
    "hide_details" : "Dé ìsọfúnni kékeré",
    "show_details" : "Fi ìsọfúnni kékeré hàn",
    "upto": "kò tóbi ju ${value}",
    "discount": "Pamọ́ ${value}%",
    "gift_card_amount": "owó ìyókù káàdì",
    "bill_amount": "Iye ìwé owó",
    "you_pay": "Ẹ sàn",
    "tip": "Owó àfikún:",
    "custom": "Ohun t'á ti pààrọ̀",
    "by_cake_pay": "láti ọwọ́ Cake Pay",
    "expires": "Ó parí",
    "mm": "Os",
    "yy": "Ọd",
    "online": "Lórí ayélujára",
    "offline": "kò wà lórí ayélujára",
    "gift_card_number": "Òǹkà káàdì ìrajì",
    "pin_number": "Òǹkà ìdánimọ̀ àdáni",
    "total_saving": "Owó t'ẹ́ ti pamọ́",
    "last_30_days": "Ọ̀jọ̀ mọ́gbọ̀n tó kọjà",
    "avg_savings": "Ìpamọ́ l’óòrèkóòrè",
    "view_all": "Wo gbogbo nǹkan kan",
    "active_cards": "Àwọn káàdì títàn",
    "delete_account": "Pa ìṣàmúlò",
    "cards": "Àwọn káàdì",
    "active": "Ó títàn",
    "redeemed": "Ó lílò",
    "gift_card_balance_note": "Àwọn káàdì ìrajà t'á lò nínú irú kan ìtajà tíwọn ṣì ní owó máa fihàn ḿbí",
    "gift_card_redeemed_note": "Àwọn káàdì ìrajà t'á lò nínú irú kan ìtajà t'ẹ́ ti lò máa fihàn ḿbí",
    "logout": "Jáde",
    "add_tip": "Fún owó àfikún",
    "percentageOf": "láti ${amount}",
    "is_percentage": "jẹ́",
    "search_category": "Wá nínú ẹgbẹ́",
    "mark_as_redeemed": "Fún orúkọ lílò",
    "more_options": "Ìyàn àfikún",
    "awaiting_payment_confirmation": "À ń dúró de ìjẹ́rìísí àránṣẹ́",
    "transaction_sent_notice": "Tí aṣàfihàn kò bá tẹ̀síwájú l'áàárín ìṣẹ́jú kan, ẹ tọ́ olùṣèwádìí àkójọpọ̀ àti ímeèlì yín wò.",
    "agree": "Jọ rò",
    "in_store": "A níyí",
    "generating_gift_card": "À ń dá káàdì ìrajà t'á lò nínú irú kan ìtajà",
    "payment_was_received": "Àránṣẹ́ yín ti dé.",
    "proceed_after_one_minute": "Tí aṣàfihàn kò bá tẹ̀síwájú l'áàárín ìṣẹ́jú kan, ẹ tọ́ ímeèlì yín wò.",
    "order_id": "Àmì ìdánimọ̀ ti ìbéèrè",
    "gift_card_is_generated": "A ti dá káàdí ìrajà t'á lò nínú irú kan ìtajà",
    "open_gift_card": "Ṣí káàdí ìrajà t'á lò nínú irú kan ìtajà",
    "contact_support": "Bá ìranlọ́wọ́ sọ̀rọ̀",
    "gift_cards_unavailable": "A lè fi Monero, Bitcoin, àti Litecoin nìkan ra káàdí ìrajà t'á lò nínú irú kan ìtajà lọ́wọ́lọ́wọ́",
    "introducing_cake_pay":  "Ẹ bá Cake Pay!",
    "cake_pay_learn_more": "Láìpẹ́ ra àti lo àwọn káàdí ìrajà t'á lò nínú irú kan ìtajà nínú áàpù!\nẸ tẹ̀ òsì de ọ̀tún láti kọ́ jù.",
    "automatic": "Ó máa ń ṣàdédé",
    "fixed_pair_not_supported": "A kì í ṣe k'á fi àwọn ilé pàṣípààrọ̀ yìí ṣe pàṣípààrọ̀ irú owó méji yìí",
    "variable_pair_not_supported": "A kì í ṣe k'á fi àwọn ilé pàṣípààrọ̀ yìí ṣe pàṣípààrọ̀ irú owó méji yìí",
    "none_of_selected_providers_can_exchange": "Àwọn ilé pàṣípààrọ̀ yíyàn kò lè ṣe pàṣípààrọ̀ yìí",
    "choose_one": "Ẹ yàn kan",
    "choose_from_available_options": "Ẹ yàn láti àwọn ìyàn yìí:",
    "custom_redeem_amount": "Iye owó l'á máa ná",
    "add_custom_redemption": "Tẹ̀ iye owó t'ẹ́ fẹ́ ná",
    "remaining": "ìyókù",
    "delete_wallet": "Pa àpamọ́wọ́",
    "delete_wallet_confirm_message" : "Ṣó dá ẹ lójú pé ẹ fẹ́ pa àpamọ́wọ́ ${wallet_name}?",
    "low_fee": "Owó àfikún kékeré",
    "low_fee_alert": "Ẹ ń fi owó àfikún kékeré fún àwọn àránṣẹ́ yín lágbára. Eleyìí lè pẹ́ gba àránṣẹ́ yín. Ó sì lè dá àwọn iye mìíràn t'á ṣẹ́ owó sí. Ó sì lè pa àwọn pàṣípààrọ̀. A dábàá pé k'ẹ́ lo owó àfikún títobi láti ṣe àṣejèrè.",
    "ignor": "Ṣàìfiyèsí",
    "use_suggested": "Lo àbá",
    "do_not_share_warning_text" : "Ẹ kò pín wọnyìí sí ẹnikẹ́ni. Ẹ sì kò pin wọnyìí sí ìranlọ́wọ́. Ẹnikẹ́ni lè jí owó yín! Wọ́n máa jí owó yín!",
    "help": "ìranlọ́wọ́",
    "all_transactions": "Gbogbo àwọn àránṣẹ́",
    "all_trades": "Gbogbo àwọn pàṣípààrọ̀",
    "connection_sync": "Ìkànpọ̀ àti ìbádọ́gba",
    "security_and_backup": "Ìṣọ́ àti ẹ̀dà nípamọ́",
    "create_backup": "Ṣẹ̀dà nípamọ́",
    "privacy_settings": "Ààtò àdáni",
    "privacy": "Ìdáwà",
    "display_settings": "Fihàn àwọn ààtò",
    "other_settings": "Àwọn ààtò mìíràn",
    "require_pin_after": "Ẹ nílò òǹkà ìdánimọ̀ àdáni láàárín",
    "always": "Ní gbogbo àwọn ìgbà",
    "minutes_to_pin_code": "${minute} ìṣẹ́jú",
    "disable_exchange": "Pa ilé pàṣípààrọ̀",
    "advanced_privacy_settings": "Àwọn ààtò àdáni títóbi",
    "settings_can_be_changed_later": "Ẹ lè pààrọ̀ àwọn ààtò yìí nínú ààtò áàpù t’ó bá yá",
    "add_custom_node": "Fikún apẹka títun t'ẹ́ pààrọ̀",
    "disable_fiat": "Pa owó tí ìjọba pàṣẹ wa lò",
    "fiat_api": "Ojú ètò áàpù owó tí ìjọba pàṣẹ wa lò",
    "disabled": "Wọ́n tí a ti pa",
    "enabled": "Wọ́n tíwọn ti tan",
    "tor_only": "Tor nìkan",
    "unmatched_currencies": "Irú owó ti àpamọ́wọ́ yín kì í ṣe irú ti yíya àmì ìlujá",
    "contact_list_contacts": "Àwọn olùbásọ̀rọ̀",
    "contact_list_wallets": "Àwọn àpamọ́wọ́ mi",
    "bitcoin_payments_require_1_confirmation": "Àwọn àránṣẹ́ Bitcoin nílò ìjẹ́rìísí kan. Ó lè lo ìṣéjú ogun tàbí ìṣéjú jù. A dúpẹ́ fún sùúrù yín! Ẹ máa gba ímeèlì t'ó bá jẹ́rìísí àránṣẹ́ náà.",
    "send_to_this_address" : "Ẹ fi ${currency} ${tag}ránṣẹ́ sí àdírẹ́sì yìí",
    "arrive_in_this_address" : "${currency} ${tag} máa dé sí àdírẹ́sì yìí",
    "do_not_send": "Ẹ kò ránṣ",
    "error_dialog_content": "Àṣìṣe ti dé.\n\nẸ jọ̀wọ́, fi àkọsílẹ̀ àṣìṣe ránṣẹ́ sí ẹgbẹ́ ìranlọ́wọ́ wa kí áàpù wa bá túbọ̀ dára.",
    "scan_qr_code": "Yan QR koodu",
    "cold_or_recover_wallet": "Fi owo aisan tabi yiyewo owo iwe iwe",
    "please_wait": "Jọwọ saa",
    "sweeping_wallet": "Fi owo iwe iwe wofo",
    "sweeping_wallet_alert": "Yio kọja pada si ikan yii. Kì yoo daadaa leede yii tabi owo ti o ti fi se iwe iwe naa yoo gbe.",
    "invoice_details": "Iru awọn ẹya ọrọ",
    "donation_link_details": "Iru awọn ẹya ọrọ ti o funni",
    "anonpay_description": "Ṣe akọkọ ${type}. Awọn alabara le ${method} pẹlu eyikeyi iwo ise ati owo yoo wọle si iwe iwe yii.",
    "create_invoice": "Ṣe iwe iwe",
    "create_donation_link": "Ṣe kọọkan alabara asopọ",
    "optional_email_hint": "Ṣeto imọ-ẹrọ iye fun owo ti o gbọdọjọ",
    "optional_description": "Ṣeto ẹru iye",
    "optional_name": "Ṣeto orukọ ti o ni",
    "clearnet_link": "Kọja ilọ oke",
    "onion_link": "Kọja ilọ alubosa",
    "decimal_places_error": "Oọ̀rọ̀ ayipada ti o wa ni o dara julọ",
    "edit_node": "Tun awọn ọwọnrin ṣiṣe",
    "frozen_balance": "Aferugbo Iye",
    "settings": "Awọn aseṣe",
    "sell_monero_com_alert_content": "Kọ ju lọwọ Monero ko ṣe ni ibamu",
    "error_text_input_below_minimum_limit" : "Iye jọwọ ni o kere ti o wọle diẹ",
    "error_text_input_above_maximum_limit" : "Iye jọwọ ni o yẹ diẹ ti o wọle diẹ",
    "show_market_place" :"Wa Sopọ Pataki",
    "prevent_screenshots": "Pese asapọ ti awọn ẹrọ eto aṣa",
    "modify_2fa": "Fi iṣiro 2FA sii Cake",
    "disable_cake_2fa": "Ko 2FA Cake sii",
    "question_to_disable_2fa":"Ṣe o wa daadaa pe o fẹ ko 2FA Cake? Ko si itumọ ti a yoo nilo lati ranse si iwe iwe naa ati eyikeyi iṣẹ ti o ni.",
    "disable": "Ko si",
    "setup_2fa": "Ṣeto Cake 2FA",
    "verify_with_2fa": "Ṣeẹda pẹlu Cake 2FA",
    "totp_code": "Koodu TOTP",
    "please_fill_totp": "Jọwọ bọ ti ẹrọ ti o wọle ni 8-digits ti o wa ni eto miiran re",
    "totp_2fa_success": "Pelu ogo! Cake 2FA ti fi sii lori iwe iwe yii. Tọ, mọ iye ẹrọ miiran akojọrọ jẹki o kọ ipin eto.",
    "totp_verification_success" :"Ìbẹrẹ dọkita!",
    "totp_2fa_failure": "Koodu ti o daju ko ri. Jọwọ jẹ koodu miiran tabi ṣiṣẹ iwe kiakia. Lo fun 2FA eto ti o ba ṣe ni jẹ 2FA ti o gba idaniloju 8-digits ati SHA512.",
    "enter_totp_code": "Jọwọ pọ koodu TOTP.",
    "add_secret_code":"Fọya koodu iye yii si eto miiran",
    "totp_secret_code":"Koodu iye TOTP",
    "important_note": "Iwọ nikan nipasẹ iwe iṣẹ kan",
    "setup_2fa_text": "Cake 2FA kii ṣe nipasẹ aisan tabi ni akoso aisan. 2FA ti ṣe pada ninu awọn iṣẹ pataki, bi atilẹyin ti o fun iṣẹ rẹ ti o ti jẹ saanu.\n\n Cake 2FA kii ṣe pada ninu atilẹyin ti o ti ba alabara kan ti o sise gidi gan.\n\n Ti o ba pọ akosile rẹ 2FA, O YOO RI ATOJU SI IWE IWE NA. O yoo nilo lati yan pẹlu iwe iwe ni o ba ṣe iṣẹ rẹ. O ni aṣẹ iru ki o gba asise akojọ iwe iwe rẹ! Nitori a ko ni aṣẹ pẹlu ohun ti o ba ṣe iṣẹ rẹ lati yan pẹlu akojọ iwe iwe rẹ, nitori Cake ni iwe iwe ti ko se iṣẹ itumọ.",
    "setup_totp_recommended": "Sọ TOTP (Kẹṣọdọ)",
    "disable_buy": "Ko iṣọrọ ọja",
    "disable_sell": "Ko iṣọrọ iṣọrọ"
}